Testo World Best - Rybeena feat. Teee Dollar
Testo della canzone World Best (Rybeena feat. Teee Dollar), tratta dall'album Virtuoso
(Ẹnu pór? Okay, motigbó)
(Ẹnu é, ẹnu é, k'olè tò ẹnu pó)
(B', Busy)
(Ló f'ẹnu pór, wáfi dè'bì)
Teee Dollar, Ogbaa
Mm-mmm, mm-mm (Choose)
Ọmọ Iya 'Dewale oh
Shout-out s'áwọn tò má pè mi world best
Mò gb'adurá pè, "ibì t'ẹtin mu, kònitan nbe" (kònitan nbe)
Ọmọ kan shò-shò bi èyàn hundred
Even Granpa ni "Rybeena l'àwọn gan njẹ" (l'àwọn gan njẹ)
Cyber truck k'oshéé fun ọlé
Richard Millie cost a Lambo', kòsirọ nbe (kòsirọ nbe)
Sometimes, wèrèy l'áfi port ẹ
T'óbá ti lò emotion, ọmọ iya mi, ò ti gok ẹ
Buss down, Richard Millie on my wrist
'Cause nobody dey when I dey warm my beans
Drive by pẹlu baba 4Matic áti bad bitch, sh'álè pè k'òló Paris?
Ogba Presido gan mọ'ru mi
As an OG, má f'ágidi shèè fáári
Mò dé lè wọ Amiri, kin tu wọ Khapy, it's going (it's going)
Kò s'òwò n'lè, ni mòfi wèrèy port ẹ
Hundred l'áti 4:30, titi dè 12:10, on God
Mò jáde tan, k'ọmọ kami mọ'bẹ
T'òbá dẹti m'òsu, ọmọ iyami, sááre lock ẹ
As a smart boy, ọmọ tio gb'òmi s'óbẹ (s'óbẹ)
Mò má l'ówó gan, áti kólẹ (kólẹ)
Pull up in a Ferrari or Maybach
Jẹka shè'ère ló si Icebox, á má gbè jet (gbè jet)
You wan dey whine me, ti mòti gb'ọjá yo (gb'ọjá yo)
But, I fit change wallet, sheb'èmi ọmọ òrò
You know for my street, na Lungu Boy dey jó
Ọgbá wá on a low
Wèrèy pór l'Eko (wèrèy pór l'Eko)
Buss down, Richard Millie on my wrist
'Cause nobody dey when I dey warm my beans
Drive by pẹlu baba 4Matic áti bad bitch, sh'álè pè k'òló Paris?
Ogba Presido gan mọ'ru mi
As an OG, má f'ágidi shèè fáári
Mò dé lè wọ Amiri, kin tu wọ Khapy, it's going (it's going)
Pull up in a Ferrari or Maybach
Jẹka shè'ère ló si Icebox, á má gbè jet
Buss down, Richard Millie on my wrist
'Cause nobody dey when I dey warm by beans
Credits
Writer(s): Demilade Olaosebikan, Adewale Atanda, Olabinjo Ayotunde Quam, Samuel Olubodun, Ayopelumi Olatunji, Saheeb Habeeb Daniel
Lyrics powered by www.musixmatch.com
Link
Disclaimer:
i testi sono forniti da Musixmatch.
Per richieste di variazioni o rimozioni è possibile contattare
direttamente Musixmatch nel caso tu sia
un artista o
un publisher.