Testo Agba Singing - Rybeena
Testo della canzone Agba Singing (Rybeena), tratta dall'album Virtuoso
Ọmọ Iya 'Dewale
Yeah-ah, oh-oh-ah
Ọmọ ọgbon, rọju show your workings, no long talk (no long talk)
Ṣh'omá gbọ? You know truth is bitter, kolanut
Me and you, one on one
Ṣh'olè bámi gbá facing, ball on ball? (Ball on ball)
Ẹ lọ kọ, soon I'm gonna chill with Elon Musk
Ṣh'omọ pè ile áyè yi, kolọ titi? (Kolọ titi rárá)
IQ l'ogbá, ṣh'omọ kogbagidi (kogbagidi ye)
When I'm no more, kofi nkàn ranti mi, ah (when I'm no more, when I'm no more)
Pè Rybeena kàn wá, ágbá singing, oh-ah
Ṣh'omọ pè ile áyè yi, kolọ titi? (Jẹjẹ l'áyè yi gbá)
IQ l'ogbá, ṣh'omọ kogbagidi (ojè lo l'áyè yi oh)
When I'm no more, kofi nkàn ranti mi, ah (when I'm no more, when I'm no more)
Pè Rybeena kàn wá, ágbá singing, oh-ah
Say, Inna a'tainaa kal kauthar
Fasalli-li rabbika wanhar
Inna shaani'aka huwal abtar
Moti mọ nkàn tóh j'ogun lọ, na Quran mimọ
Jẹn sọh otito, Ọlọhun mi nbẹ bi âtijọ
Kolọ ibi kànkàn
Oh pass èwè, èlèwè o j'èwè (èwèkèwè)
Ah, mogbè, Baraka o sun'lè (oh-ohh)
T'an j'èwè, use your life dey play (dey play oh)
Mm, eke, o ti di gbègbè-gbè
Pass èwè, èlèwè o j'èwè (èwèkèwè)
Ah, mogbè, Baraka o sun'lè (oh-ohh)
T'an j'èwè (oh-ah), use your life dey play (dey play oh)
Mm, eke, o ti di gbègbè-gbè
Ṣh'omọ pè ile áyè yi, kolọ titi? (Kolọ titi rárá)
IQ l'ogbá, ṣh'omọ kogbagidi (kogbagidi ye)
When I'm no more, kofi nkàn ranti mi, ah (when I'm no more, when I'm no more)
Pè Rybeena kàn wá, ágbá singing
Ṣh'omọ pè ile áyè yi, kolọ titi? (Pass èwè, èlèwè o j'èwè)
IQ l'ogbá, ṣh'omọ kogbagidi (mogbè, Baraka o sun'lè)
When I'm no more, kofi nkàn ranti mi, ah (t'an j'èwè, use your life dey play)
Pè Rybeena kàn wá, ágbá singing (eke, o ti di gbègbè-gbè)
Credits
Writer(s): Damilola Yisa, Atanda Adewale
Lyrics powered by www.musixmatch.com
Link
Disclaimer:
i testi sono forniti da Musixmatch.
Per richieste di variazioni o rimozioni è possibile contattare
direttamente Musixmatch nel caso tu sia
un artista o
un publisher.