Testo Omo Olona - 9ice

Testo della canzone Omo Olona (9ice), tratta dall'album Lord Of Ajasa

(Nakhit)
Aitete mọna lo jẹ kọna jin
Ọmọ ọlọna, ọmọ ọlọna
Fun mi lọna ki n maa lọ
Abeere ọna ki i ṣina
Ọmọ ọlọna, ọmọ ọlọna
Fun mi lọna ki n maa lọ
Ẹṣin to kọ sare
Ni gbogbo igba iran lọ maa wo kẹyin
Ọba ṣa lalade
Mo fori balẹ
Jinwin-jinwin ilẹkẹ
University ti mi o lọ
Ọrẹ mi to lọ ko ṣetan
Wọn ni n kọṣẹ, emi kọ
Ọrẹ mi ti o kọ lo pawo
Gbọnmi si omi wọn o to
Labalaba digbo lẹgun
Ẹgun to gun mi, emi peregun
Mo parọda, mo siregun
Aitete mọna lo jẹ kọna jin
Ọmọ ọlọna, ọmọ ọlọna
Fun mi lọna ki n maa lọ
Abeere ọna ki i ṣina
Ọmọ ọlọna, ọmọ ọlọna
Fun mi lọna ki n maa lọ
Ẹṣin to kọ sare
Ni gbogbo igba iran lọ maa wo kẹyin
Ọba ṣa lalade
Mo fori balẹ
Jinwin-jinwin ilẹkẹ o
Nigba kan ri, mi o ṣe mu yangan
Wọn ni mama mi jami lẹnu ọyan
Jagidijagan pọ
Ko ki n gbọ, ko ki n gba
A gba bọọlu a kan lẹsẹ
A kawe, kawe ori dọta
Still, a kere oko dele
Ah, igba tẹni to lọna de
Oun ta da'wọle yọri si rere
O da bi ara loju ọmọ araye
Emi kọ, ọlọna lo n tọna
Ọlọna lo n ṣ'ọna
Onile lo nile
Alara gbayida, Baba mi
Kabiesi o!
Ọlọna lo n tọna
Abeere ọna o ni ṣina
To kọ sare
Iran lọ maa wo gbẹyin
Ọna ti mo tọ lo ṣamọna mi
Ọba ṣa lalade
Jinwin-jinwin ilẹkẹ o
(It's Bizzle on the mix)



Credits
Writer(s): Alexander Abolore Adegbola Akande
Lyrics powered by www.musixmatch.com

Link

Disclaimer: i testi sono forniti da Musixmatch.
Per richieste di variazioni o rimozioni è possibile contattare direttamente Musixmatch nel caso tu sia un artista o un publisher.

Altre canzoni dell'album

Elenco artisti

© 2026 Riproduzione riservata. Rockol.com S.r.l.
Policy uso immagini

Rockol

  • Utilizza solo immagini e fotografie rese disponibili a fini promozionali (“for press use”) da case discografiche, agenti di artisti e uffici stampa.
  • Usa le immagini per finalità di critica ed esercizio del diritto di cronaca, in modalità degradata conforme alle prescrizioni della legge sul diritto d'autore, utilizzate ad esclusivo corredo dei propri contenuti informativi.
  • Accetta solo fotografie non esclusive, destinate a utilizzo su testate e, in generale, quelle libere da diritti.
  • Pubblica immagini fotografiche dal vivo concesse in utilizzo da fotografi dei quali viene riportato il copyright.
  • È disponibile a corrispondere all'avente diritto un equo compenso in caso di pubblicazione di fotografie il cui autore sia, all'atto della pubblicazione, ignoto.

Segnalazioni

Vogliate segnalarci immediatamente la eventuali presenza di immagini non rientranti nelle fattispecie di cui sopra, per una nostra rapida valutazione e, ove confermato l’improprio utilizzo, per una immediata rimozione.