Testo Ere - 9ice
Testo della canzone Ere (9ice), tratta dall'album Lord Of Ajasa
Owo mo wa pa, mi o ba toṣí wa o
Ere mo wa ṣe, mi o ba tija wa o
Enemies dey beside me, ṣugbọn, mi o ri wọn
Wọn pariwo nita, ṣugbọn, mi o gbọ wọn
Gbogbo aroye wọn ko ma ye mi
A o wa ṣere o (a o wa ṣere o)
A o wa ṣere o (a o wa ṣere o)
Ọmọ ta gbe wa ko kekere o
Ija lẹ ba wa, a o wa ṣere o (a o wa ṣere o)
Mo ti pẹ n'ta tipẹ o (pẹ n'ta gan-an)
Mo ti pẹ n'ta tipẹ o (pẹ n'ta gan-an ni)
Mo ṣe ere ọmọde ti pe o (pẹ n'ta gan-an)
Mo ti daye tipẹ o
Ẹ wa-wa, oh-oh
Ẹ wa-wa, oh-oh
Ẹ wa-wa, oh-oh
Ere mo wa ṣe, mi o ba tija wa o
Owo mo wa pa, mi o ba toṣí wa o
Music in my vein, mi o ba tija wa o
Music I dey play, mi o ba toṣi wa o
Ẹ wa-wa, oh-oh (wa wo)
Ẹ wa-wa, oh-oh (wa wo)
Eh-eh, oh-oh
Enemy, I go over them
Enemy, I go over-
Enemy, I go over them
Enemy, I go over-
Enemy, I go over-
Wọn petepero, over them
Petepero, see, I'm over them, yea
Wọn lọ ile babalawo kan
Emi gan babalawo kan nibi kan
O lọ ile oniṣegun kan
Emi gan-an wọn gbe iwe fun mi nibi kan
Ah! Emi ọmọ Ajibọla ọmọ Ẹdan
Ohun ta ba fọn fun fere yẹn ṣa lo maa fọn
Gbọ na, this season o maa yatọ
Faaji nisinyi, o kọ sisọ
See many, many things la ti ṣe ri
O ra Hennessy kan, o wa fẹ ma ba mi gbegba
I'm over them tipẹ-tipẹ ni
Mo ma ti mọ ìtọwo ibẹ tipẹ-tipẹ gan-an
Me I ran all over them tipẹ-tipẹ
Me, I just dey gboju n bẹ, emi ọmọ ọpẹ
I'm over them
Enemies, I'm over them
Apetepero, over them still
Adigun over them, babalawo
Gbese re o
Gbese re fun awọn ọta mi
Gbese re o
Gbese re fun awọn ẹni ibi
Gbese re o
Gbese re fun awọn ọta mi
Gbese re o
Gbese re fun awọn ẹni ibi
You are over them, Adigun
You be on them, Adigun (Nakhit)
You are above them, Adigun o
O ju wọn lọ, Adigun tipẹ-tipẹ (it's Bizzle on the mix)
Aro kese tipẹ-tipẹ
Aro kese tipẹ-tipẹ (Opiro)
Ọwọrin-ṣe-ogbe tipẹ-tipẹ
Credits
Writer(s): Alexander Abolore Adegbola Akande
Lyrics powered by www.musixmatch.com
Link
Disclaimer:
i testi sono forniti da Musixmatch.
Per richieste di variazioni o rimozioni è possibile contattare
direttamente Musixmatch nel caso tu sia
un artista o
un publisher.