Rockol30

Testo Kokanmi - Qdot

Testo della canzone Kokanmi (Qdot), tratta dall'album Alagbe

Òní wàràpá tí rọlú mágún (kasa!)
Ko kan mi, ko kan mi
Qdot lórúkọ mí (ko kan mi, ko kan mi)
Mo mọ pe ẹ mọ mí lẹ ṣé ń f'ọbọ lọ mi
Mí o l'órí, lo gùn pé ibọn ó lé rán mí
Bíbélì mo ní pẹlú Qurani
Pẹlú kí ní báà mí tó ń dùn woro-woro
Ẹní f'ojú dí iná, iná à jo
Ìyá Ìbàdàn, ó yà, gb'àgbo lè'ná
Èpò ọgẹdẹ kò lé yọ mí
Máa pẹ bí Aláàfin Ọyọ ní
Wèrè ní wọn, mó má lé wọn s'Aro
Má gbé wọn lọ bí t'òdò Ìyá Aláró
Ẹ fún mí l'hammer, kí n fọ wọn lórí ká
Àwọn wèrè, àwọn motherfucker
Ẹ ro dáadáa kẹ to b'Èṣù lówé
Ẹ sọ fún Ṣígidi, kò má r'odò lọ wẹ
Kí ló ń jẹ' kò s'ewé, kò s'egbò nínú àyé?
K'Ọlọrun májẹ à rí'já àyé ní
Ṣi-ọ, kẹlẹbẹ (ko kan mi)
Wọn ní pé picker die (ko kan mi)
Pé client ó sọrọ mọ (ko kan mi)
Pé ìyàwó yín ṣé oloṣo (ko kan mi)
Ó n sún yàrá landlord (ko kan mi)
Wọn fẹ mọ idí abájọ (ko kan mi)
Ta ní Bàbá Alájọ? (Ko kan mi)
Ẹ re ilé bàbálawo (ko kan mi)
Ẹbọ yìn má fọ m'awo (ko kan mi)
Wọn ni pé Yahoo ní (ko kan mi)
Wọn ni pé à ṣ'ogun owó (ko kan mi)
Òní wàràpá rọlú mágùn (ko kan mi)
Pé lagbaja b'ójú kọ'rin (ko kan mi)
Ẹní òyìnbó ó dùn lẹnu mí (ko kan mi)
But local mí ń ja'wó (ko kan mi)
Òkè Kilimanjaro sọ pé Ọlumọ ó gá
À gbọ' t'ajá, à gbọ' t'ẹran
Èwo ní t'àgùntàn lórí àga
Wọn ní mọ local, mo ń pa'wó lọ
Ọmọ Folashade, mo tí gba'dé lọ
Òyìnbó lé má dùn lẹnu mí
Èyí tí ń bá sọ, Wole Soyinka l'aba yìn tu
Ẹ wá wo ẹlẹkọ tó yàn'dì s'oní moi-moi
Òní bùgan bínú ẹlẹ́wà àgóyìn
I don't care if you like or not
Ẹní ṣíṣẹ ló má pa'wó
Kòkòrò tó ń jó leba ọna ní, onílù rẹ ń bẹ nínú igbó
Mó tí gòkè, mó tí ṣé lọ k'afara tó já
Mó japa, k'òyìnbó tó já
Ọmọdé àná tí wá d'àgbà
Qdot, ọmọ imalẹ afeleja
Ẹ ro dáadáa kẹ to b'Èṣù lówé
Ẹ sọ fún Ṣígidi, kò má r'odò lọ wẹ
Kí ló ń jẹ' kò s'ewé, kò s'egbò nínú àyé?
K'Ọlọrun májẹ à rí'já àyé ní
Ṣi-ọ, kẹlẹbẹ (ko kan mi)
Wọn ní pé picker die (ko kan mi)
Pé client ó sọrọ mọ (ko kan mi)
Pé ìyàwó yín ṣé oloṣo (ko kan mi)
Ó n sún yàrá landlord (ko kan mi)
Wọn fẹ mọ idí abájọ (ko kan mi)
Ta ní Bàbá Alájọ? (Ko kan mi)
Ẹ re ilé bàbálawo (ko kan mi)
Ẹbọ yìn má fọ m'awo (ko kan mi)
Wọn ni pé Yahoo ní (ko kan mi)
Wọn ni pé à ṣ'ogun owó (ko kan mi)
Òní wàràpá rọlú mágùn (ko kan mi)
Pé lagbaja b'ójú kọ'rin (ko kan mi)
Ẹní òyìnbó ó dùn lẹnu mí (ko kan mi)
But local mí ń ja'wó (ko kan mi)
Jirafa jalika ra fali eli Malaika mí Orimọlade
Ẹní f'ojú dí iná, iná à jo
Ìyá Ìbàdàn, ó yà, gb'àgbo lè'ná
Èpò ọgẹdẹ kò lé yọ mí
Máa pẹ bí Aláàfin Oyo ní
K Sir Sosse
King of Marley
Musa Felix for Garuba
Femi Jaguar nílùú London
Mo mọ Baddy Oosha
Lanre Typical
Milli ọmọ Salawe
Mo mọ Femi Chill Music
Mo mọ Billique (mo mọ Billi')
Mo mọ Doctor Brown
Mo mọ Arowolo, Arowolo tí ń tá motor
Mo mọ Bottles, IBD Dende
Aláṣẹ Nikas Teni Level
Mo tí mọ Water
Mo mọ Owo Mabo
Bunmi simple casher
Mo mọ Unique Motors
Mo mọ Climax
Mo mọ Pasuma Wonder, ọmọ ìyàwó Anọbi l'Omole
Xsmile
(Yeah, who's here?)
Quick as sure boys



Credits
Writer(s):
Lyrics powered by www.musixmatch.com

Link

Disclaimer: i testi sono forniti da Musixmatch.
Per richieste di variazioni o rimozioni è possibile contattare direttamente Musixmatch nel caso tu sia un artista o un publisher.

Elenco artisti

© 2025 Riproduzione riservata. Rockol.com S.r.l.
Policy uso immagini

Rockol

  • Utilizza solo immagini e fotografie rese disponibili a fini promozionali (“for press use”) da case discografiche, agenti di artisti e uffici stampa.
  • Usa le immagini per finalità di critica ed esercizio del diritto di cronaca, in modalità degradata conforme alle prescrizioni della legge sul diritto d'autore, utilizzate ad esclusivo corredo dei propri contenuti informativi.
  • Accetta solo fotografie non esclusive, destinate a utilizzo su testate e, in generale, quelle libere da diritti.
  • Pubblica immagini fotografiche dal vivo concesse in utilizzo da fotografi dei quali viene riportato il copyright.
  • È disponibile a corrispondere all'avente diritto un equo compenso in caso di pubblicazione di fotografie il cui autore sia, all'atto della pubblicazione, ignoto.

Segnalazioni

Vogliate segnalarci immediatamente la eventuali presenza di immagini non rientranti nelle fattispecie di cui sopra, per una nostra rapida valutazione e, ove confermato l’improprio utilizzo, per una immediata rimozione.