Rockol30

Testo Gbese - Qdot feat. Niniola

Testo della canzone Gbese (Qdot feat. Niniola), tratta dall'album Alagbe

Ẹ ra motor 150 thousand, ẹnì ko ma taku lóru
Ẹ tí jonz (ẹ jonz)
Ẹ ti jonz (ẹ jonz)
Nini dé
(Ẹ jonz)
Ẹ gb'ọtí lẹ, kẹ jonz
Ẹnu o, ẹnu, ọrọ ẹnu important
Ẹnu lẹnu temi, máfi bèrè òun tó dára
Ko ma gbàgbé mí, Ẹlẹdàá mí
Irè pàdé mí
Jẹlosimi, lọ jókò (ẹ lọ jókò)
Ẹ kéré gan-an, ẹ tí pọ tó (ẹ tí pọ tó)
Bàbá Ìjẹbú fún mí l'ẹyọkan
Fún mí ní number kí n jẹ, kí n tà tẹtẹ ẹ
Àre tí bèrè, kẹ suure síbí
Ẹ t'ara ṣáṣá ké gbé soolu, kìí body yìn tẹle
Mójú kẹlẹlẹ, b'òṣùpá bà yọ k'aṣeré alẹ (kúrò ń bẹ)
You really wanna turn the party down?
Party don turn on a boggy-boogy down, go down, well done
I like the way you do
When there's life, there is hope
Believe in yourself, don't belittle yourself
(Wolo, wolo-wolo wolo-wolo)
(Gb'ẹsẹ) gb'ẹsẹ sókè o (gb'ẹsẹ)
Gbé body sókè o (gb'ẹsẹ)
Ọmọ ológo gbéra tan (gb'ẹsẹ)
Jí, má sún (gb'ẹsẹ)
Ẹnì ṣáṣẹ l'agbowó (gb'ẹsẹ)
Ọlọhun o ṣ'ojoró (gb'ẹsẹ)
Nkuyo, owo mi dá o? (Gb'ẹsẹ)
Ẹ máa jẹ ko japa o (gb'ẹsẹ)
Gb'ẹsẹ sókè oh (gb'ẹsẹ)
Gbé body sókè o (gb'ẹsẹ)
(Kúrò ń bẹ) goat dey dance, aboki dey laugh
Goat no know say aboki wan use am for suya
Òyìnbó ní, "Life is vocabulary, methaphorlosis
Life is concogariculous," ọrọ lẹṣín òwe
T'ẹmi bawa, ìrètí ń bẹ
Kola Olawuyi ní Nkan Ńbẹ
Nítorí ọbọ o j'ọgẹdẹ mọ, owo l'ejo ń jẹ
Gbogbo slay mama, come and miliki to my music
It's very unique, nourish bí ti miliki
Kiki, do you love me?
Are you riding? Do you really want me?
T'Olubadan bá wọ knicker burger, bọọlu ló fẹ lọ gbà (gbà-gbá-gbà)
To ba rí NEPA to ń lo laptop, bo ya wire lo fí n ja
(Gb'ẹsẹ) gb'ẹsẹ sókè o (gb'ẹsẹ)
Gbé body sókè o (gb'ẹsẹ)
Ọmọ ológo gbéra tan (gb'ẹsẹ)
Jí, má sún (gb'ẹsẹ)
Ẹnì ṣáṣẹ l'agbowó (gb'ẹsẹ)
Ọlọrun o ṣ'ojoró (gb'ẹsẹ)
Nkuyo, owo mi dá o? (Gb'ẹsẹ)
Ẹ máa jẹ ko japa o (gb'ẹsẹ)
Àwọn ọmọ benefit (gb'ẹsẹ)
Cotonou wọ Port Novo (gb'ẹsẹ)
Gbé body sókè o
Àwọn slay mama t'ọn bà tí rí Snapchat
Wọn a tọ'jú, t'ete
Wọn a demo' pẹlú flower lórí o
Jẹlosimi, lọ jókò (ẹ lọ jókò)
Ẹ kéré gan-an ẹ tí pọ tó (ẹ tí pọ tó)
Bàbá Ìjẹbú fún mí l'ẹyọkan
Fún mí ní number kí n jẹ, kí n tà tẹtẹ ẹ
(Gb'ẹsẹ) gb'ẹsẹ sókè oh (gb'ẹsẹ)
Gbé body sókè oh (gb'ẹsẹ)
Xsmile, bámí lu'lu (gb'ẹsẹ)
Wọn tún tí jẹ mi lówó (gb'ẹsẹ)
IBD Dende (gb'ẹsẹé)
Mo mọ Sir Kuti (gb'ẹsẹ)
Mo mọ Femi Jaguar (gb'ẹsẹ)
Lanre Typical (gb'ẹsẹ)
Òrìṣà ní Baddy Oosha oh (gb'ẹsẹ)
Arowolo ló ń ta motor oh (gb'ẹsẹ)
Òun ta motor ni Texas (gb'ẹsẹ)
K Sir, Sosse (gb'ẹsẹ)
King of Marley (gb'ẹsẹ)
Ọba Bombay (gb'ẹsẹ)
Àkúré Oloyemẹkun (gb'ẹsẹ)
Mo mọ Hot Water oh (gb'ẹsẹ)
Èèyàn Iko Modina (gb'ẹsẹ)
Aremọ Gucci (gb'ẹsẹ)
Kẹhinde Fatai mi (gb'ẹsẹ)
Tata, Emeka (gb'ẹsẹ)
Niyass King Chievo (gb'ẹsẹ)
Aláṣẹ Nikas, Teni level ní (gb'ẹsẹ)
Ọmọ Ọba Kumasi (gb'ẹsẹ)
Lekan Agbainọki (gb'ẹsẹ)
Mo mọ Billique (gb'ẹsẹ)
Mo mọ Milli Hustle (gb'ẹsẹ)
Ọtunba Cash (gb'ẹsẹ)
Abu Abel (gb'ẹsẹ)
Wọn laa ji wọn lorin kọ (gb'ẹsẹ)
Ìyẹn lá ṣe tún kọ (gb'ẹsẹ)
Uh-uh, uh-uh-nh
(Yeah, who's here?)



Credits
Writer(s): Niniola Apata, Remilekun Safaru, Michael Alagwu
Lyrics powered by www.musixmatch.com

Link

Disclaimer: i testi sono forniti da Musixmatch.
Per richieste di variazioni o rimozioni è possibile contattare direttamente Musixmatch nel caso tu sia un artista o un publisher.

Elenco artisti

© 2025 Riproduzione riservata. Rockol.com S.r.l.
Policy uso immagini

Rockol

  • Utilizza solo immagini e fotografie rese disponibili a fini promozionali (“for press use”) da case discografiche, agenti di artisti e uffici stampa.
  • Usa le immagini per finalità di critica ed esercizio del diritto di cronaca, in modalità degradata conforme alle prescrizioni della legge sul diritto d'autore, utilizzate ad esclusivo corredo dei propri contenuti informativi.
  • Accetta solo fotografie non esclusive, destinate a utilizzo su testate e, in generale, quelle libere da diritti.
  • Pubblica immagini fotografiche dal vivo concesse in utilizzo da fotografi dei quali viene riportato il copyright.
  • È disponibile a corrispondere all'avente diritto un equo compenso in caso di pubblicazione di fotografie il cui autore sia, all'atto della pubblicazione, ignoto.

Segnalazioni

Vogliate segnalarci immediatamente la eventuali presenza di immagini non rientranti nelle fattispecie di cui sopra, per una nostra rapida valutazione e, ove confermato l’improprio utilizzo, per una immediata rimozione.