Testo Ife - Ibrahim Maalouf feat. Angelique Kidjo
Testo della canzone Ife (Ibrahim Maalouf feat. Angelique Kidjo), tratta dall'album Queen of Sheba
Oni iyawo ogota
Ninou awon obinrin to lèwa gan
Ati okpolokpo
Ati okpolokpo
Ma gbagbé awon ogori alè, tè nin
Ati gbogbo awon tara ijoba rè
Ati okpolokpo
Makeda
Makeda
Makeda
Ti won ni ikoko ifè foun yin
Shugbon, lale yi mori ninu
Oju yin
Ati okpolokpo, ati okpolokpo
Kpé okan obinrin kan lo n'da yin l'odju
Ati okpolokpo
Makeda
Makeda
Makeda Eh
Kini n'kan, ta m'kpé nin imi
Kossi, ko djè ifé
Kini n'kan, ta m'kpé nin emi
Kossi, ko lè djè ifé
Eyi ti o tu kpalè kpelou agara a
Okan ènin ti o ni sokan
Kini^n'kan, ta m'kpé nin emi
Kossi, ko lè djè ifé
Ko lè djè ifé
Elo dja yé yin
Kpèlou igbadun kpikpo, kpikpo
Makeda ati okpolokpo
Ati okpolokpo
Ti eniyan ko le foju mon
Ati okpolokpo okan ibanuje
Ati okpolokpo
Makeda
Ti won ni ikoko ifè foun yin
Shugbon, lale yi mori ninu
Oju yin
Ati okpolokpo, ati okpolokpo
Kpé okan obinrin kan lo n'da yin l'odju
Ati okpolokpo
Makeda
Nin sinko èwa kodju mon min
Nin sinko èwa kodju mon min
Lesso m'kpé omi ti mon moun
Omi aafin rè, Emin mon ji nin
Kini n'kan, ta m'kpé nin imi
Ife ti mou ni foun e ni, Makeda
Kini n'kan, ta m'kpé nin èmi
Ife ti mou ni foun e ni, Makeda
Kini n'kan, ta m'kpé nin imi
Kossi, ko djè ifé
Kini n'kan, ta m'kpé nin emi
Kossi, ko lè djè ifé
Eyi ti o tu kpalè kpelou agara a
Okan ènin ti o ni sokan
Kini n'kan, ta m'kpé nin imi
Kossi, ko djè ifé
Kini n'kan, ta m'kpé nin emi
Kossi, ko lè djè ifé
Eyi ti o tu kpalè kpelou agara a
Okan ènin ti o ni sokan
Kini n'kan, ta m'kpé nin imi
Kossi, ko djè ifé
Kini n'kan, ta m'kpé nin emi
Kossi, ko lè djè ifé
Eyi ti o tu kpalè kpelou agara a
Okan ènin ti o ni sokan
Kini n'kan, ta m'kpé nin imi
Kossi, ko djè ifé
Kini n'kan, ta m'kpé nin emi
Kossi, ko lè djè ifé
Eyi ti o tu kpalè kpelou agara a
Okan ènin ti o ni sokan
Kini^n'kan, ta m'kpé nin emi
Kossi, ko lè djè ifé
Ko lè djè ifé
Credits
Writer(s): Philip Glass
Lyrics powered by www.musixmatch.com
Link
Disclaimer:
i testi sono forniti da Musixmatch.
Per richieste di variazioni o rimozioni è possibile contattare
direttamente Musixmatch nel caso tu sia
un artista o
un publisher.