Testo Eyin - Ibrahim Maalouf feat. Angelique Kidjo
Testo della canzone Eyin (Ibrahim Maalouf feat. Angelique Kidjo), tratta dall'album Queen of Sheba
Solomoni ti won so foun mi, m'kpé oti yan,
O jisè rè l'aarin awon èyè
Solomoni ti won so foun mi, m'kpé oti yan,
O farè ofin ati ogbon si won léri
Shugbon ojé ajeji èyè kan, nin emi lati soro si o
Sibé ni èyè ti èmon rara ni min lati soro si nin sin
Shugbon ojé ajeji èyè kan, nin emi lati soro si o
Oro èyè ti èmon rara èyè igolu
Eyè yi koni èran
Eyè yi koni èjè
Eyè yi koni iyè
Awo rè ni wipè, èwa goolu
Eyè yi olé wa ku
Eyè yi olè wa l'ayé
Eyè yi ko yéra
Ni ibààlè ati doundoun miliki
Biribiri rè pipè, to dabi ilé ayé
Biribiri rè pipè, to dabi ilé ayé
Biribiri rè pipè, to dabi ilé ayé
Biribiri rè pipè, to dabi ilé ayé
Solomoni, won so foun mi kpé, ègbadoun orin
Égbadoun awon orin alapandédé
Solomoni, won so foun mi kpé, ègbadoun orin
N'tori ojé adjéji èyè kan ni emi la ti soro si o
Shugbon ojé adjéji èyè kan ni emi la ti soro si o
Sibé ni èyè ti eèmon rara ni mon lati soro si nin sin
Shugbon ojé adjéji èyè kan ni emi la ti soro si o
Oro èyè ti èmon rara èyè igolu
Eyè yi koni èran
Eyè yi koni èjè
Eyè yi koni iyè
Awo rè ni wipè, èwa goolu
Eyè yi olé wa ku
Eyè yi olè wa l'ayé
Eyè yi ko yéra
Ni ibààlè ati doundoun miliki
Eyè yi koni èran
Eyè yi koni èjè
Eyè yi koni iyè
Awo rè ni wipè, èwa goolu
Eyè yi olé wa ku
Eyè yi olè wa l'ayé
Eyè yi ko yéra
Ni ibààlè ati doundoun miliki
Biribiri nin pipè (biribiri nin pipè)
To dabi ilé ayé (to dabi ilé ayé)
Biribiri nin pipè (biribiri nin pipè)
To dabi ilé ayé (to dabi ilé ayé)
Biribiri nin pipè
To dabi ilé ayé
Biribiri nin pipè
To dabi ilé ayé
Credits
Writer(s): Angelique Kidjo, Ibrahim Maalouf
Lyrics powered by www.musixmatch.com
Link
Disclaimer:
i testi sono forniti da Musixmatch.
Per richieste di variazioni o rimozioni è possibile contattare
direttamente Musixmatch nel caso tu sia
un artista o
un publisher.