Testo Ganja - Rybeena
Testo della canzone Ganja (Rybeena), tratta dall'album Mr Bee
(Coz-Coz-Cozmicaudio)
(Japh Kenti, Kenti)
T'òbá ti dè mulè, wọn á nipè "ṣ'òmá nbá?"
Má gbáá, t'òbá ti fẹ l'ápá
Ganja, everyday l'ámá n fá
Ọmọ boys dem with hin own trauma (trauma, trauma)
I don see devil wey wear sutana
L'Ajah, mò ri pẹlu kala, gangstar
Wèrèy pọr ni Naija, I no get choice
When I check my available (ahh-ahh, ahh)
I see say na only me go carry my ágbèlèbu
'Cause everything no dey happen by miracle (ahh, ahh-wooh)
And daddy mi dẹti try gàn, now, èmi l'òku
Ṣugbọn áti kọ, má lá, ò dáju (ahh-ahh, ahh)
Nigbámi, gbògbò nkàn kọ gàn l'òn wọmi l'òju
Sáni Sátáni, yámi, y'èṣu (ahh, ahh-wooh)
Wetin I no fit see no dey controllable
Mòn lọ jẹjẹ mi niò
Igi gògòrò, má gùn mi l'òju
Át'òkèrè má ṣáti gb'òju
Òrin nimò mọ, tò dá mi l'òju
Òju yẹn ṣá l'òmọ òun tò yò'nu
Mò mọ ibi mòn lọ, ẹ má kànmi l'òju
Ademil'eke, wọn'lè dámi durò
Ẹru mi tò pọr l'òṣuká fi wuwò, ye-ahh
Wọn á ni "Mr. Bee" (wọn á ni "Mr. Bee")
Ọgá òlòrin tòun pámi bi ọti (ọgá òlòrin tòun pámi bi ọti)
Ọdọ ẹgbẹ ẹ gàn ò jẹ fi ẹ tá'yin
Ágbá ni leather, máfi wè khaki
Hey, át'áwọn fine girls melanin
Oyinbo mi pepper gàn ni, dákun, má pámi
Ẹbọrá rhythm, Lord of Harmony
Òtun lè kọ Fuji l'òri RnB (uh-uhnn)
T'òbá ti dè mulè, wọn á nipè "ṣ'òmá nbá?"
Má gbáá, t'òbá ti fẹ l'ápá
Ganja, everyday l'ámá n fá
Ọmọ boys dem with hin own trauma (trauma, trauma)
I don see devil wey wear sutana
L'Ajah, mò ri pẹlu kala, gangstar
Wèrèy pọr ni Naija, I no get choice
When I check my available
I see say na only me go carry my ágbèlèbu
'Cause everything no dey happen by miracle
And daddy mi dẹti try gàn, now, èmi l'òku
Ṣugbọn áti kọ, má lá, ò dáju
Nigbámi, gbògbò nkàn kọ l'òn wọmi l'òju
Sáni Sátáni, yámi, y'èṣu
Wetin I no fit see no dey controllable
Mòn lọ jẹjẹ mi niò
Igi gògòrò, má gùn mi l'òju
Át'òkèrè má ṣáti gb'òju
Òrin nimò mọ, tò dá mi l'òju
Òju yẹn ṣá l'òmọ òun tò yò'nu
Mò mọ ibi mòn lọ, ẹ má kànmi l'òju
Ademil'eke, wọn'lè dámi durò
Ẹru mi tò pọr l'òṣuká fi wuwò, ye-ahh
(Thank you for your peaceful cooperation)
(Japh Kenti)
Wọn á ni "Mr. Bee" (wọn á ni "Mr. Bee")
Ọgá òlòrin tòun pámi bi ọti (ọgá òlòrin tòun pámi bi ọti)
Credits
Writer(s):
Lyrics powered by www.musixmatch.com
Link
Disclaimer:
i testi sono forniti da Musixmatch.
Per richieste di variazioni o rimozioni è possibile contattare
direttamente Musixmatch nel caso tu sia
un artista o
un publisher.