Testo Tọkọ Tìyàwó - K1 De Ultimate
Testo della canzone Tọkọ Tìyàwó (K1 De Ultimate), tratta dall'album Let The Music Flow Vol. 2
Ọrọ t'ọkọ t'ìyàwó la fẹ sọ o (ọrọ t'ọkọ t'ìyàwó la fẹ sọ o)
Ọrọ t'ọkọ t'ìyàwó la fẹ sọ o (ọrọ t'ọkọ t'ìyàwó la fẹ sọ o)
Ẹni sàn owó kọkọrọ lọ ń l'aya ní le
Eyan ti ó san ó ama dá nìkan sún
Ada sun bàbá ada jí òtútù a fẹ sa ẹ pa
Ẹni sàn owó kọkọrọ lọ ń l'aya ní le
Eyan ti ó san ó ama dá nìkan sún
Ada sun bàbá ada jí òtútù a fẹ sa ẹ pa
Obá tètè sanwo iba sọrọ
Fún àwọn ẹbí ìyàwó k'arẹwà kò le wa ó (kí arẹwà kò le wa ó)
Obá tètè sanwo iba sọ'rọ'
Fún àwọn ẹbí ìyàwó k'arẹwà kò le wa ó (kí arẹwà kò le wa ó)
Mo ní ko ya tètè sanwo iba sọ'rọ'
Fún àwọn ẹbí ìyàwó k'arẹwà kò le wa ó (kí arẹwà kò le wa ó)
Ìyàwó ẹ kò wálé, ìyàwó ẹ kò wálé (ìyàwó ẹ kò wálé)
Ki ìyàwó ẹ kò wálé, ìyàwó ẹ kò wálé (ìyàwó ẹ kò wálé)
Inkan gidi ni fún ọmọkùnrin to tí nisẹ lapa
Ẹpe ko lọ l'aya nílé
Ọmọ obìnrin tó ti ní ń tonjẹ ẹsin wọn re ile ọkọ
Nítorí atètè sùn òhun la tètè jí
Gbogbo ohun dáradára tan gbe ilé ayé ṣe
Ki wọ nà ba wọn le tètè se
Ẹyin òbí ẹjẹ ka gbọrọ yí yẹwo
Kaya tètè fi adua sin wọn
Iya,baba mí bí mí, ani ké mí náà bí te mi
Torí ban ba wá délé ban bá b'ọmọ wa ń le
Bán bá bere wipe bàbá,mama ẹ ń kọ
Wọn tí wá ń jíjẹ lọ lo yẹ k'ọmọ o ma sọ
Ìyàwó ẹ kò wálé, ìyàwó ẹ kò wálé (ìyàwó ẹ kò wálé)
Obá tètè sanwo iba sọrọ
Fún àwọn ẹbí ìyàwó k'arẹwà kò le wa ó (kí arẹwà kò le wa ó)
Ohun tá bá fi fun yan, ti ẹ ti ẹ ní (ti ẹ ti ẹ ní)
Tá bá fi fun yan, ti ẹ ti ẹ ní (ti ẹ ti ẹ ní)
Ohun tá bá fi fun yan sẹ, ti ẹ ti ẹ ní (ti ẹ ti ẹ ní)
Ko ní di ti ẹniẹlẹni o, ti ẹ ti ẹ ní (ti ẹ ti ẹ ní)
Ìwọ lo san wo kọkọrọ, ti ẹ ti ẹ ní (ti ẹ ti ẹ ní)
Ati owo iba sọrọ, ti ẹ ti ẹ ní (ti ẹ ti ẹ ní)
Kẹ dẹ bí mọ aláyọ, ti ẹ ti ẹ ní (ti ẹ ti ẹ ní)
Awọn ọmọ alálùbáríkà, ti ẹ ti ẹ ní (ti ẹ ti ẹ ní)
Credits
Writer(s): Olasunkanmi Ayinde Marshal
Lyrics powered by www.musixmatch.com
Link
Disclaimer:
i testi sono forniti da Musixmatch.
Per richieste di variazioni o rimozioni è possibile contattare
direttamente Musixmatch nel caso tu sia
un artista o
un publisher.