Testo Solo Makinde - K1 De Ultimate
Testo della canzone Solo Makinde (K1 De Ultimate), tratta dall'album The Ultimate Collection
Solo Makinde oo
Ma gbọ bi mo ṣe n wi
Ma gbọ bi mo ṣ n f'orin lu sọ
Solo Makinde oo
Solo Makinde
Ẹni ti ori ba ti da o
Ori ti da ẹ na
Ẹni ti ori ba ti da o
Ori ti da ẹ na
E le pa kadara
Béèyàn kan lepa kadara lasan
Aṣọ rẹ a faya ni
O gbọ bi mo ṣe n wí
Ọmọ Gbọlahan Ayinde
Oluaye fuji mi o
Solo Makinde oo
Atẹwọ mo ba ila yi o
Mo mọ ẹni to kọ ọ
Ọmọ Gbọlahan Ayinde
Kaluku lo mori wa ile aye
Ori kaluku yatọ
Ẹ ma f'ori Tayelolu kẹ fi we ti kẹhinde o
Iya Ibeji to bi'mọ oun gangan ti mọ
Pe kaluku lo mori ẹ wa
Ẹ ma fori adifa kẹ fi we ti adẹkun, Ayinde ọmọ Gbọlahan Ayinde
Atẹwọ mo ba ila yi o, mo mọ ẹni to kọ ọ
Ọmọ Gbọlahan mi o
Abi o gbọrọ mi o
Adio Monsuru mi o, ọmọ Onikoyi ni ilu Texas
Ma gbọ bi mo ṣe n wi
Alade Anuga mi o, Latunji Lukmon Alade
Ọkọ Monisọla abi o gbọrọ mi gan
Mr. Totọ Anuga Alade
Ẹni tori ba ti da o, ori ti da ẹ na
Wọn yi le pa kadara o
Béèyàn kan lepa kadara lasan
Aṣọ rẹ a faya ni
Ọrọ ile aye o toju su mi o
Ẹlẹnu pupọ ṣa laye
Ẹnu to fi n p'ade gun lo fi n sọ pe ade o gun
Abi o gbọrọ mi o
Hennesy maa gbọrọ mi o
Monsuru lodi lawyer mi o ninu Chicago
Ma gbọ mi Basira Jọkẹ
Jọkẹ ọmọ shogunro
Aya Tekane mi o o ṣeun
Mother alhaji alhaji mi o
Ma wọle o ṣeun
Awo Kẹmi baby, Kẹmo Olukọya o
Ni New York city o, motherfucker mi o ṣeun
Nipa awọn olofofo t'ọn jẹ Solo Makinde
Ki lo n jẹ Solo Makinde o?
Awọn olofofo adugbo ni
Solo Makinde
Ofofo Berger ah igbe ọpẹ lo kan
Solo makinde, ta lo fi iṣẹ ran yin?
Eke ile, Solo Makinde
Ki lo n jẹ Solo Makinde?
Isọ awọn olofofo
Eke adugbo ni lo n jẹ Solo Makinde
Abẹnugun'bẹ pati, olofofo
Solo Makinde, a wa yin dele
A o ba yin nile
Ọmọ yin la ba to n jẹ ojuyọbọ
Atẹwọ loju wa Ayinde
Eyes kongba
Bẹ ba sọ fun wọn b'ọn o gbọ o
Wọn tun lorukọ k'eki o
Eyi to lo jẹ ọkunrin ninu Solo Makinde
Yaya lo n jẹ
Eyi to lo jẹ obinrin ninu Solo Makinde
Lo n jẹ Deborah, Ayinde
Eyes kongba o
Bẹ ba ri wọn l'ọna, ẹ wo wọn re
Ẹni ta o fi iṣẹ ran to n lọ toju bọ'le ka
Eke ile, Solo Makinde
Solo Makinde, eke yin
A wa yin dele, a o ba yin n'le
Ọmọ yin la ba to n jẹ ojuyọbọ
Ofofo loju wa, Ayinde, awọn eyes kongba o
B'ọn pemi lagbo fuji, ma ya lọ (ma jo, ma yọ)
B'ọn pemi lagbo fuji, ma ya lọ (ma jo, ma yọ)
Ma jo, ma yọ o (o ya, ma jo, ma yọ)
Ma jo, ma yọ (o ya, ma jo, ma yọ)
B'ọn pemi lagbo fuji, ma ya lọ (ma jo, ma yọ)
Ma tẹ Versace mi si (ma jo, ma yọ)
His captain instantly mafia (ma jo, ma yọ)
Ma jo, ma yọ (ma jo, ma yọ)
Dolce Gabbana, o ti lọ (ma jo, ma yọ)
His captain instantly mafia (ma jo, ma yọ)
Ma tun tẹ versace mi si (ma jo, ma yọ)
Ma ranju mo mi mọ (Solo Makinde)
Ma ranju mo mi mọ (Solo Makinde)
Iwọ nikan kọ lo loju (Solo Makinde)
Eke yin (Solo Makinde)
Awa yin dele (Solo makinde)
A o ba yin n'le (Solo makinde)
Ọmọ yin la ba (Solo makinde)
Credits
Writer(s): Olasunkanmi Ayinde Marshal
Lyrics powered by www.musixmatch.com
Link
Disclaimer:
i testi sono forniti da Musixmatch.
Per richieste di variazioni o rimozioni è possibile contattare
direttamente Musixmatch nel caso tu sia
un artista o
un publisher.