Testo Si O Olutunu Orun - EmmaOMG
Testo della canzone Si O Olutunu Orun (EmmaOMG), tratta dall'album Si O Olutunu Orun
Si o olutunu orun
Fun ore atgabara re
A nko
A nko
A nko hallelujah
Si o for eni towa
Ninu majemu olorun
A nko e
A nko
A nko hallelujah
Si o agbara eni ti
Ohun emimo to nwonisan
A nko e
A nko
A nko hallelujah
Si o oruko atore
Amona wa to to dopin
Anko e
Anko e
Si wo eniti krisiti ran
Ade oun gbogbo ebun re o
Anko e
Anko
Anko hallelujah
A nko
A nko
A nko hallelujah
Credits
Writer(s): Emmanuel Edunjobi
Lyrics powered by www.musixmatch.com
Link
Disclaimer:
i testi sono forniti da Musixmatch.
Per richieste di variazioni o rimozioni è possibile contattare
direttamente Musixmatch nel caso tu sia
un artista o
un publisher.