Rockol30

Testo Ota Mi - eLDee

Testo della canzone Ota Mi (eLDee), tratta dall'album Is It Your Money? Vol.1

ELDee e-e-e-e-e
LKT eh-eh
And another one
And another one
Ọ'tá mí o ní ya f'ọkọ
Akoyoyo ní o kàn lẹsẹ
Agbe gẹdú ní o kàn lo run
Ọmọ lanke ní o wo lẹ'yìn
Àwa má rìn bai, rìn bai, rìn bai
Àwa má rìn bai, rìn bai, rìn bai
È wá na, è wa na, e ba mi gbọ
Ẹlẹ'dà mí ní òun tí sọ
Kò sọ'nà t'ele gbé gbá wá
Kò sára t'ele fẹ wá dá
Àwa tí wo express
As He don bless, no man can test
Ko si'ṣòro, eyín lo ń stress
A'tajẹ, a'toṣó, ẹ confess
Wọn sa'rè wọn (wọn rí wá mù)
Wọn kọrin wọn (wọn rí wá mú)
Wọn tí wá lo (wọn rí wa sun)
Wọn lu gẹmbẹ (a gbọ' kò dùn)
Olúwa mí lo ń ṣìnà
Ìkà tẹ ṣe lo ń dínà
Ìrawọ́ wá e, lo ń tan'nà, lo ń tan'ná (lo ń tan'ná)
Ọ'tá mí o ní ya f'ọkọ (ya f'ọkọ)
Akoyoyo ní o kan lẹsẹ (kàn lẹsẹ)
Agbe gẹdú ní o kàn lo run (kàn lọ run)
Ọmọ lanke ní o wo lẹ'yìn (wo lẹ'yìn o)
Àwa má rìn bai (rìn bai), rìn bai, rìn bai (rìn rege-rege)
Àwa má rìn bai, rìn bai, rìn bai (atun lu raga-raga, raga-raga, raga-raga)
Ẹ tẹti, ẹ tẹti yìn kẹ gbọ mí
Bàbá God, òun lọ ń sọ mí
Làti ibẹrẹ, òun lọ ń gbọ' mí
Without Him, l am nobody
Emí de recognise
Òun lọ jẹ ka commercialize
Tá le fí le má enterprise
Ìlù to dùn àti ohùn to nice
Wọn ṣá're wọn (wọn rí wá mú)
Wọn kọrin wọn (wọn rí wá mú)
Wọn tí wá lọ (wọn rí wá sun)
Wọn lu gẹmbẹ (a gbọ ko dùn)
Olúwa mí lọ ń ṣìnà
Ìka tè ṣe lọ ń dínà
Irawo wa, lọ ń tan'ná, lọ ń tan'na (lọ ń tan'ná)
Ọ'tá mí o ni ya f'ọkọ (ya f'ọkọ)
Akoyoyo ní o kàn lẹsẹ (kàn lẹsẹ)
Agbe gedu ní o kàn lọrun (kàn lọ run)
Ọmọ lanke ní o wo lẹ'yìn (wo lẹ'yìn o)
Àwa má rìn bai, rìn bai, rìn bai
Àwa má rìn bai, rìn bai, rìn bai
T'alajá wọn pa kúrú mo?
Ta lopolo wọn dé rú bá oo?
Àwọn báwo
Ye! Lórí ọwọ wo?
Àwọn kèké oguro, tí mo tí jẹun lọ
Ye! Ẹ gbójú ń bẹ o
Ẹ jáwọ́ ń bẹ o
Bẹ̀bẹ̀ ṣí ń bẹ o
Àyé ṣí ń lọ o
Wọn ní ká m'ẹnì
Olá la má mú
È bá mí yọ o
Ko fọwọ' ṣeré, f'ọmọ ṣeré, fẹ'Hennesy ṣòwò
È sá rí o
Ọ'tá mí o ni ya f'ọkọ (ya f'ọkọ)
Akoyoyo ní o kàn lẹsẹ (kàn lẹsẹ)
Agbe gedu ní o kàn lọ run (kàn lọ run)
Ọmọ lanke ní o wo léyìn (wo lẹ'yìn o)
Àwa má rìn bai (rìn bai), rìn bai, rìn bai (rìn rege-rege)
Àwa má rìn bai, rìn bai, rìn bai (atun lu raga-raga, raga-raga, raga-raga)
Ọ'tá mí o ní ya f'ọkọ (ya f'ọkọ)
Akoyoyo ní o kàn lese (kàn lẹsẹ)
Agbe gedu ní o kàn lọ run (kàn lọ run)
Ọmọ lanke ní o wo lẹ'yìn (wo lẹ'yìn gan)
Àwa má rìn bai, rìn bai, rìn bai (ko ríran mo)
Àwa má rìn bai, rìn bai, rìn bai (rìn raga-raga ah-ah)
Wọn sá're wọn (wọn rí wá mù)
Wọn kọrin wọn (wọn rí wá mù)
Wọn tí wá lọ (wọn rí wá sun)
Wọn lu gẹmbẹ (a gbọ' kò dún)
Olúwa mí lọ ń ṣìnà
Ìka tẹ ṣe lọ ń dínà
Ìrawọ́ wa, lo ń tan'nà, lo ń tan'nà (lọ ń tan'ná)
Ọ'tá mí o ní ya f'ọkọ (ya f'ọkọ)
Akoyoyo ní o kàn lese (kàn lẹsẹ)
Agbe gedu ní o kàn l'orun (kàn lọ run)
Ọmọ lanke ní o wo lẹ'yìn (wo lẹ'yìn o)
Àwa má rìn bai (rìn bai), rìn bai, rìn bai (rìn rege-rege)
Àwa má rìn bai, rìn bai, rìn bai (atun lu raga-raga, raga-raga, raga-raga)
Ọ'tá mí o ní ya f'ọkọ (ya f'ọkọ)
Akoyoyo ní o kàn lẹsẹ (kàn lẹsẹ)
Agbe gedu ní o kàn lọ run (kàn lọ run)
Ọmọ lanke ní o wo lẹ'yìn (wo lẹ'yìn gan)
Àwa má rìn bai, rìn bai, rìn bai (ko ríran mo)
Àwa má rìn bai, rìn bai, rìn bai (rìn raga-raga ah-ah)



Credits
Writer(s): Sikirullahi Dabiri, Tunde Olalekan
Lyrics powered by www.musixmatch.com

Link

Disclaimer: i testi sono forniti da Musixmatch.
Per richieste di variazioni o rimozioni è possibile contattare direttamente Musixmatch nel caso tu sia un artista o un publisher.

Elenco artisti

© 2025 Riproduzione riservata. Rockol.com S.r.l.
Policy uso immagini

Rockol

  • Utilizza solo immagini e fotografie rese disponibili a fini promozionali (“for press use”) da case discografiche, agenti di artisti e uffici stampa.
  • Usa le immagini per finalità di critica ed esercizio del diritto di cronaca, in modalità degradata conforme alle prescrizioni della legge sul diritto d'autore, utilizzate ad esclusivo corredo dei propri contenuti informativi.
  • Accetta solo fotografie non esclusive, destinate a utilizzo su testate e, in generale, quelle libere da diritti.
  • Pubblica immagini fotografiche dal vivo concesse in utilizzo da fotografi dei quali viene riportato il copyright.
  • È disponibile a corrispondere all'avente diritto un equo compenso in caso di pubblicazione di fotografie il cui autore sia, all'atto della pubblicazione, ignoto.

Segnalazioni

Vogliate segnalarci immediatamente la eventuali presenza di immagini non rientranti nelle fattispecie di cui sopra, per una nostra rapida valutazione e, ove confermato l’improprio utilizzo, per una immediata rimozione.