Testo Osu Mi, Mio Riro - K1 De Ultimate

Testo della canzone Osu Mi, Mio Riro (K1 De Ultimate), tratta dall'album Flavours Vol. 1

Osu mí,mi o riro (mi o riro)
Alo osu mí ó,mi o riro (mi o riro)
Mo lo su mi,mi o riro (mi o riro)
Ẹba jẹ ka sayé rẹ,k'àyé ba se wa re(k'àyé ba se wa re)
Mo ni ẹ jẹ ka sayé rẹ,k'àyé ba se wa re(k'àyé ba se wa re)
Ewo ní ka lonjẹ ka ma bebi sún
Kani na ka ma sun lookun
Kani ilé ọmọ Nigeria katun má sún ẹ'bá ọ'nà ó
Osu mí,mio riro (mi o riro)
Ọrọ yi kan yín ẹyin ijoba ó
Ọgẹdẹ nbajẹ ẹ pe opọn
Ọrọ yi kan yín ẹyin ijoba
Ọgẹdẹ nbajẹ ẹ pe opọn
Ọmọ kàwé tan won o rí ìsẹ ti o d'owo
Owa sọ ọmọkùnrin d'olẹ, ó sọ ọmọbìnrin di nabi ó
Bẹ kẹ làwọn kan wa epo ẹ ó rí ńṣe
Ọgẹdẹ nbajẹ ẹ pe opọn
Àwọn kan wa epo ẹ ó rí ńṣe
Ọgẹdẹ nbajẹ ẹ pe opọn
Ẹyin ìjọba ẹro tọ la mo o
Ka se réré sílẹ k'àyé to tan
Ẹyin ìjọba ẹro tọ la mo o
Ka se réré sílẹ k'àyé to tan
Ọmọ olówó lon tan ná
Ọgẹdẹ nbajẹ ẹ pe opọn
Kokan yín bá ralu oba níná
Ọgẹdẹ nbajẹ ẹ pe opọn
Ìyà njẹ ará ìlú ẹ o ri ńṣe
Ka se réré sílẹ k'àyé to tan
Torí un tẹ bá se lawa má wi ó
Ẹyin oselu ẹ ronú
Èyí tẹ bá se lawa má sọ
Ẹyin oselu ẹ ronú
Ẹro ọrọ yí jìnlẹ ẹ ro dáàda
Ẹyin oselu ẹ ronú
Ìdájọ Ọlọhun mi ku si dẹdẹ-dẹdẹ
Ka se réré sílẹ k'àyé to tan
Mon bọ wá Ọlọhun o ya l'ogún ọdún
Ka se réré sílẹ k'àyé to tan
Mon bọ wá Ọlọhun o ya l'ogún ọdún o
Ka se réré sílẹ k'àyé to tan
Tèmí ye mí ó,Olúayé oni fuji (tèmí ye mí)
Temí ye mí i ó
To ri ẹ mo se sọ ọmọ gègè (tèmí ye mí)
T'onjẹ ọmọ ba jinná ko ma se jo mi lẹnu
Ti ire ọmọ ba de tan,ko ṣojú ẹ'mí mí o
To ri bẹ mo se sọ ọmọ gègè (tèmí ye mí)
Àní t'onjẹ ọmọ ba jinná,ko ma se jo mi lẹnu
Ti ire ọmọ ba de tan,ko ṣojú ẹmí mí
To ri bẹ mo se sọ ọmọ gègè (tèmí ye mí)
Ọkọ Lolade Jẹmilatu (tèmí ye mí)
Baba Bobade Riliwanu (tèmí ye mí)
To ri bẹ mo se sọ ọmọ gègè (tèmí ye mí)
Olúwafẹmi Sotirẹ (tèmí ye mí)
T'ọjú Yalu Wabilahi Taofeek o (tèmí ye mí)
Awo ọmọlàjà n'ilu Germany mi (tèmí ye mí)
T'ọjú Lash ọmọ Asorobi (tèmí ye mí)
To ri bẹ mo se sọ ọmọ gègè o (tèmí ye mí)
To ri ẹ mo se sọ ọmọ gègè (tèmí ye mí)
To ri bẹ mo se sọ ọmọ gègè (tèmí ye mí)



Credits
Writer(s): Olasunkanmi Ayinde Marshal
Lyrics powered by www.musixmatch.com

Link

Disclaimer: i testi sono forniti da Musixmatch.
Per richieste di variazioni o rimozioni è possibile contattare direttamente Musixmatch nel caso tu sia un artista o un publisher.

Elenco artisti

© 2026 Riproduzione riservata. Rockol.com S.r.l.
Policy uso immagini

Rockol

  • Utilizza solo immagini e fotografie rese disponibili a fini promozionali (“for press use”) da case discografiche, agenti di artisti e uffici stampa.
  • Usa le immagini per finalità di critica ed esercizio del diritto di cronaca, in modalità degradata conforme alle prescrizioni della legge sul diritto d'autore, utilizzate ad esclusivo corredo dei propri contenuti informativi.
  • Accetta solo fotografie non esclusive, destinate a utilizzo su testate e, in generale, quelle libere da diritti.
  • Pubblica immagini fotografiche dal vivo concesse in utilizzo da fotografi dei quali viene riportato il copyright.
  • È disponibile a corrispondere all'avente diritto un equo compenso in caso di pubblicazione di fotografie il cui autore sia, all'atto della pubblicazione, ignoto.

Segnalazioni

Vogliate segnalarci immediatamente la eventuali presenza di immagini non rientranti nelle fattispecie di cui sopra, per una nostra rapida valutazione e, ove confermato l’improprio utilizzo, per una immediata rimozione.