Testo Oonirisa Ogunwusi - K1 De Ultimate

Testo della canzone Oonirisa Ogunwusi (K1 De Ultimate), tratta dall'album Let The Music Flow Vol. 1

Yorùbá mọ ohun toda
Wọn mọ ohun toda
Wọn l'aṣa tó wùn mí ó
Lo ṣe wú mi lórí ó, wípé mo jẹ Yorùbá
Ẹyin Ọba ládéládé, ẹ kú àmójúbà o
Kábíyèsí Ọọniriṣa ó
Yorùbá mọ ohun toda
Wọn mọ' ohun toda o
Wọn mọ' ohun toda o
Wọn l'aṣa tó wùn mí ó
Lo ṣe wú mi lórí ó, wípé mo jẹ Yorùbá
Ẹyin Ọba ládéládé, ẹ kú àmójúbà o
Kábíyèsí Ọọniriṣa ó
Kábíyèsí Ọba tótó bí aró
Ọba rẹrẹ' bí osùn
Arọbafin l'ọba ń pá
Mo wolẹ, mo pagun mọwọ, Ọọniriṣa ó
Kábíyèsí Ọba tótó bí aró
Ọba rẹrẹ' bí osùn
Arọbafin l'ọba ń pá
Mọ wolẹ, mo pagun mọwọ, Ọọniriṣa ó
Adéyẹye ọba ó (ọba ó)
Ọba Adéyẹye, ọba ó (ọba ó)
Kábíyèsí leni ó, Ẹnitan Ọba Adéyẹye
Ọmọ Ògúnwusi ó
Kaa fa sórí àlééfà
Gbogbo wá lo n kan Ọba
B'ọba bá tide igà
Oníkálukú a wólẹ' fún Ọba ní
Arọbafin l'ọba ń pa
Adéyẹye ọba ó (ọba ó)
Ẹwí fún wọn nílé alárá, ẹ sọ nílé ajerò
Àrólé Odùduwà Ọjájá ti de, Ọba Adéyẹye ó
Ṣẹkẹrẹ, agogo, ohún la ń jo ń'lé ọba
Ṣẹkẹrẹ, agogo, ohún la ń jo ń'lé ọba
Ẹyin Arọbafin kẹ sọra, kẹ má jìyà
Ṣẹkẹrẹ, agogo, ohún la ń jo ń'lé ọba
Ẹyin Arọbafin, ẹ sọra, kẹ má jìyà
Ṣẹkẹrẹ, agogo, ohún la ń jo ń'lé ọba
Arobafin, ẹ sọra, kẹ má jìyà
Ṣẹkẹrẹ, agogo, ohún la ń jo ń'lé ọba
Káàbọ' sílé ó (káàbọ' sílé ó)
Káàbọ' sílé ó (káàbọ' sílé ó)
Àrólé Oodua ó (káàbọ' sílé ó)
Àrólé Oodua (káàbọ' sílé ó)
Kábíyèsí, Ọba Ẹnitan Adéyẹye
Ọmọ t'Ogunwusi, Ọjájá the second
Ọọniriṣa Ìlú Ifẹ
Àrólé Oodua ó (káàbọ' sílé ó)
Ọba Adéyẹye (káàbọ' sílé ó)
Deyẹye, ọmọ Ogunwusi (káàbọ' sílé ó)
Arẹgbẹṣọla Raufu, fọba jẹ (káàbọ' sílé ó)
Desọji ọkọ Bidemi, fọba jẹ (káàbọ' sílé ó)
Igba ẹ a tu wá lara (káàbọ' sílé ó)
Asiko yii a tu wa lara (káàbọ' sílé ó)
Elegusi ni ńki ọba (káàbọ' sílé ó)
Ọba Demọla Saheed ó (káàbọ' sílé ó)
King Gucci ni ńki ọba (káàbọ' sílé ó)
Arẹmọ Oniru pẹlú Akin Ṣiku
Ni ńki ọba (káàbọ' sílé ó)
Àrólé Oodua ó (káàbọ' sílé ó)
Mo k'ara awọn Ọọniriṣa, mo kí wọn ní Ìwó ilé
Ìwó ọmọ Odòọba, Ọmọba tóni mere ó
Mọrọ itoṣi, owó ńlá ńlá
Ẹrú wẹwẹ nà fí n delé ní Ìwó
Akú amojuba ọba tuntun o
Àlàyélúwà, Ọba Adewale Akanbi Rosheed
Ìwó, mo kí yín, Oluaye fuji
Ogbó atọ t'ọba niṣe ó, t'ọba niṣe
Káàbọ' sílé ó (káàbọ' sílé ó)
Gbogbo Ìkòdú oriu
Ọmọ Ẹluku Mẹdẹmẹdẹ, Ẹluku Mẹdẹmedẹ
Wumale Ọmọ Afèlèjà
Aku Àmo'júbà, Ayangburẹ tuntun o
Ọba Adewale, Ọba Shotobi ó ní Ikòdú
Káàbọ' sílé ó (káàbọ' sílé ó)
Àrólé Oodua ó (káàbọ' sílé ó)
Àsìkò yín a tu wa lára (káàbọ' sílé ó)
Ìgbà yìí a tu wa lara (káàbọ' sílé ó)
Àsìkò yíi a tu wa lára (káàbọ' sílé ó)
Káàbọ' sílé ó (káàbọ' sílé ó)



Credits
Writer(s): Olasunkanmi Ayinde Marshal
Lyrics powered by www.musixmatch.com

Link

Disclaimer: i testi sono forniti da Musixmatch.
Per richieste di variazioni o rimozioni è possibile contattare direttamente Musixmatch nel caso tu sia un artista o un publisher.

Elenco artisti

© 2026 Riproduzione riservata. Rockol.com S.r.l.
Policy uso immagini

Rockol

  • Utilizza solo immagini e fotografie rese disponibili a fini promozionali (“for press use”) da case discografiche, agenti di artisti e uffici stampa.
  • Usa le immagini per finalità di critica ed esercizio del diritto di cronaca, in modalità degradata conforme alle prescrizioni della legge sul diritto d'autore, utilizzate ad esclusivo corredo dei propri contenuti informativi.
  • Accetta solo fotografie non esclusive, destinate a utilizzo su testate e, in generale, quelle libere da diritti.
  • Pubblica immagini fotografiche dal vivo concesse in utilizzo da fotografi dei quali viene riportato il copyright.
  • È disponibile a corrispondere all'avente diritto un equo compenso in caso di pubblicazione di fotografie il cui autore sia, all'atto della pubblicazione, ignoto.

Segnalazioni

Vogliate segnalarci immediatamente la eventuali presenza di immagini non rientranti nelle fattispecie di cui sopra, per una nostra rapida valutazione e, ove confermato l’improprio utilizzo, per una immediata rimozione.