Testo Mo Wa Lati J'osin - EmmaOMG
Testo della canzone Mo Wa Lati J'osin (EmmaOMG), tratta dall'album OhEmGee Praise Sessions, Vol. 1
Oh my God!
(ìbèrè orin)
ìmólè ayé
Ósòkalè nú òkùnkùn
Sí ojú mi kîn rí o
ìfé tó'mu
Kí okàn mi ma júbà rè
ìrètí fún ayé pèlú'e
(ÈGBÈ)
Mowá lati jósìn
Mowá lati teríba
Mowá lati so wípé
ìwo l'olorun mi
L'àpapò ìwo lótósí
L'àpapò ìwo leni're
L'àpapò ìyanu lojé sími
Oba ayérayé
Tówà níbi gíga
Nínú ògo lókè òrun
Ófi ìrèlè wá
sínú ayé tí odá
Nítorí ìfé od'aláìní
(ÈGBÈ)
Mowá lati jósìn
Mowá lati teríba
Mowá lati so wípé
ìwo l'olorun mi
L'àpapò ìwo lótósí
L'àpapò ìwo leni ire
L'àpapò ìyanu lojé sími
(ÈGBÈ)
Mowá lati jósìn
Mowá lati teríba
Mowá lati so wípé
ìwo l'olorun mi
L'àpapò ìwo lótósí
L'àpapò ìwo leni ire
L'àpapò ìyanu lojé sími
Nkò lèmò iye tójé
Láti r'èsè mi lórí àgbélèbú
Nkò lèmò iye tójé
Láti rí èsè mi lórí àgbélèbú
Nkò lèmò iye tójé
Láti rí èsè mi lórí àgbélèbú
(i would never know
How much it cost to see my sin)
(ÈGBÈ)
Mowá lati jósìn
Mowá lati teríba
Mowá lati so wípé
ìwo l'olorun mi
L'àpapò ìwo lótósí
L'àpapò ìwo leni ire
L'àpapò ìyanu lojé sími
Mowá lati jósìn
Mowá lati teríba
Mowá lati so wípé
ìwo l'olorun mi
L'àpapò ìwo lótósí
L'àpapò ìwo leni ire
L'àpapò ìyanu lojé sími
(ìparí orin)
Olorun tó dà àwon òkè ìgbanì
Èyin ni mofi Opé mi fún
Credits
Writer(s):
Lyrics powered by www.musixmatch.com
Link
Disclaimer:
i testi sono forniti da Musixmatch.
Per richieste di variazioni o rimozioni è possibile contattare
direttamente Musixmatch nel caso tu sia
un artista o
un publisher.