Testo Iba - 9ice
Testo della canzone Iba (9ice), tratta dall'album Afro Juju
(Speedomile)
Ah-ah!
Milẹ ti, ti, ti
Ah-ah (Skill mix dot com)
Mo júbà Akọdá o (ibà)
Mo júbà Aṣẹ̀dá o (ibà)
Ibà babaláwo (ibà)
Ibà àwọn ẹlẹgbẹ' oo (ibà)
Ọ̀pá ká yọ látẹ, Alagogo Idẹ, iba yín o (ibà)
Ibà tí mo du, kò ṣẹ, kò ṣẹ, kò ṣẹ ní tí lakọ ṣẹ
Ẹgbẹ tí mo níi, wọn ń bẹ, wọn dúró tí mí, wọn jẹ'hùn gbé
Ibà rẹ o, Olódùmarè, ẹni to l'odu, to mobi tí mare, eh-eh
Ibà rẹ o
Kí ni wọn o fí mí ṣe?
Kí ni wọn o fí mí ṣe?
Odigba o ṣe
Àta matáse
Ọmọ ọlọtọ má lọ, jọ (má lọ, jọ)
Ọmọ ọlọfọ, má p'ọfọ (má p'ọfọ)
Òkìtì kàn bí o tí o balaye
Koti-koti fa, bi o ṣe f'araye
Òkìtì kàn bi tí bu b'araye
Òun tí ń kọbi ko bi ni f'arayée
Mo júbà Akọdá o (ibà)
Mo júbà Aṣẹ̀dá o (ibà)
Ibà babaláwo (ibà)
Ibà àwọn ẹlẹgbẹ' oo (ibà)
Ọpá ká yọ látẹ Alagogo Idẹ, ibà yín o (ibà)
Ibà tí mo du, kò ṣẹ, kò ṣẹ, kò ṣẹ ní tí lako ṣẹ
Ẹgbẹ tí mọ níí, wọn ń bẹ, wọn dúró tí mí, wọn jẹ'hùn gbé
Ibà rẹ o, Olódùmarè, ẹni to l'odu, to mobi tí mare, eh-eh
Ibà rẹ o
(It's Bizzle on the mix)
Credits
Writer(s):
Lyrics powered by www.musixmatch.com
Link
Disclaimer:
i testi sono forniti da Musixmatch.
Per richieste di variazioni o rimozioni è possibile contattare
direttamente Musixmatch nel caso tu sia
un artista o
un publisher.