Testo E E Soro - Dagrin

Testo della canzone E E Soro (Dagrin), tratta dall'album Still On The Matter

Ẹyin témí
Mó mọ pé ẹ ti ń retí mí ti pé
Ẹlòmíì rò pé mó tí kù, mọ tí kù sí pańpẹ́
But mọ dupẹ wípé mi ti deni yẹpẹ
É bami ji Tolulope kò wá bá mi sọ pé
Àwọn èèyàn o mọ mi, wọn pe ni ináà
Won ni mo f'ori, f'imu mi jo Obinna
Ọmọ Yorùbá ni mí
Wọn bimi pelu ayọ'
Mọ ti sọ fún yín pe ki e ye pè mí ni Anayo
Àwọn èèyàn ṣòro, wọn ni mi o gbó òyìnbó
Mọ'fé bẹ'rẹ' lọwọ yin, se òyìnbó gbó Yorùbá?
Mi ó sé ọmọ NewYork
Ọmọ Èkó ni mí ti e ba ti rimi ewo ko need ki e bí mi
Ó fe mó Ẹbí mí, ó fẹ' mó màmá to bí mi
Mo fun e láyé, kò lo bẹ'rẹ' lọ'wọ' Baby mi, a ṣàlàyé bi mo se je aráyé
Ìjọ kàn náà kò ni wọn bi emi pẹlu Falaye
Eyín tèmi, mọ' wọlé de, É sọ'rọ'
Yín ti e tin rẹ tí mi tipe, É ṣòro
Mọ' dé ti wọlé dé ní yẹn, É sọ'rọ'
É sọ'rọ', É sọ'rọ'
Eyín tèmi, mọ' wọlé de, É sọ'rọ'
Ẹyin ti e tin rẹ tí mi tipe, É ṣòro
Ọ' dé ti wọlé dé ní yẹn, É sọ'rọ'
É sọ'rọ', É Ṣòro
Áì tí ṣe tán, men am still on the matter
Orin si pọ lẹ'nu mi jaburata
Kò wo pátá, ko wo bata, ki o to Bósítà
So that wa le jó mo dáadáa bii Shina Peters
Etí mọ mi, mi ki n change weather
Rap léni, ko fuji lola, lai! Never!
E de ti mo mi, am real, am better
Ìsìn yín le ma mo pe kaki no be leather
Timba call wọn, wọn tun gbé wá
Everytime láyé mi lé mi n kéré wá
Where am from, eh! Èkó ni mọ ti wa
Life ti mo n live l'eko o ti romilorun
Nítorí Ọlọ'run èwo chain tí mo ko s'orun
Àwọn ṣíṣí fún mi kiss láì ṣe Jadakiss, Ludacris, ejo!
Eyín tèmi, mọ' wọlé de, É sọ'rọ'
Yín ti e tin rẹ tí mi tipe, É ṣòro
Mọ' dé ti wọlé dé ní yẹn, É sọ'rọ'
É sọ'rọ', É sọ'rọ'
Eyín tèmi, mọ' wọlé de, É sọ'rọ'
Ẹyin ti e tin rẹ tí mi tipe, É ṣòro
Ọ' dé ti wọlé dé ní yẹn, É sọ'rọ'
É sọ'rọ', É Ṣòro
Igba ti mọ tí ní business pẹ'lú Leo
T'awon tèmi bá rí mi wọn àní Grin (yee)
Èwo mí nísinsìnyí, mó ń jẹun mó ń yọ nisinyin, mi o ń jẹun n
Mo ni yà kò yọ
Mii ó sé bolo, I'm a big Bobo
Ema fimiwe, ewo mo ti kúrò lewe
Tí ó ba like orin mi, leave! (Get away)
T'awon girls bá rí mi, won wàhálà mí
Àwọn guys wọn léṣe kí wọn má holla mi
Won áni "please jo sign mí ní autograph"
Mo fé bá e yá photograph
Wọn ni fi ẹlòmíì ṣé mi
Where am from?
Mi o ti kú, timba sọ'rọ' ẹyọ kàn, won àní mo n fóònù
Grin baba! Ọ'sẹ' ọmọ
Ó yá é lenu
Eyín tèmi, mọ' wọlé de, É sọ'rọ'
Yín ti e tin rẹ tí mi tipe, É ṣòro
Mọ' dé ti wọlé dé ní yẹn, É sọ'rọ'
É sọ'rọ', É sọ'rọ'
Eyín tèmi, mọ' wọlé de, É sọ'rọ'
Ẹyin ti e tin rẹ tí mi tipe, É ṣòro
Ọ' dé ti wọlé dé ní yẹn, É sọ'rọ'
É sọ'rọ', É Ṣòro
Leo Entertainment
We are still on the matter mehn
Nothin dey do us, still on the street
Yeah! Haha!



Credits
Writer(s): Oladapo Olaitan Olaonipekun
Lyrics powered by www.musixmatch.com

Link

Disclaimer: i testi sono forniti da Musixmatch.
Per richieste di variazioni o rimozioni è possibile contattare direttamente Musixmatch nel caso tu sia un artista o un publisher.

Elenco artisti

© 2026 Riproduzione riservata. Rockol.com S.r.l.
Policy uso immagini

Rockol

  • Utilizza solo immagini e fotografie rese disponibili a fini promozionali (“for press use”) da case discografiche, agenti di artisti e uffici stampa.
  • Usa le immagini per finalità di critica ed esercizio del diritto di cronaca, in modalità degradata conforme alle prescrizioni della legge sul diritto d'autore, utilizzate ad esclusivo corredo dei propri contenuti informativi.
  • Accetta solo fotografie non esclusive, destinate a utilizzo su testate e, in generale, quelle libere da diritti.
  • Pubblica immagini fotografiche dal vivo concesse in utilizzo da fotografi dei quali viene riportato il copyright.
  • È disponibile a corrispondere all'avente diritto un equo compenso in caso di pubblicazione di fotografie il cui autore sia, all'atto della pubblicazione, ignoto.

Segnalazioni

Vogliate segnalarci immediatamente la eventuali presenza di immagini non rientranti nelle fattispecie di cui sopra, per una nostra rapida valutazione e, ove confermato l’improprio utilizzo, per una immediata rimozione.