Testo Birthday Praise - EmmaOMG
Testo della canzone Birthday Praise (EmmaOMG), tratta dall'album Birthday Praise
Oh my God
S'ọba tó jókò sórí ìtẹ' mímọ, tá wọn angẹli kọrin sí
Ní mọ wá sọ wípé (ìbà rẹ ó)
O joko lórí obiri ayé ọba awọn ọba (ìbà rẹ ó)
Otitibiri aji p'ọjọ ikú dá, awuwo má ṣe gbé (ìbà rẹ ó)
Gbanigbani l'ọjọ ogun lè, gbanigbani tá ń sa yà (Ìbà rẹ ó)
Yaagbo, yaaju, ọkunrin ogun
Ijilẹ ifẹ, aládé wúrà (ìbà rẹ ó)
Ọlọ́run mimọ tí kò s'abawon kankan nínú rẹ (ìbà rẹ ó)
Igbá tó borí igbá, agbára tó borí agbára
Erujẹjẹ (ìbà rẹ ó)
Jehovah jireh, Jehovah shammah
El shaddia, Jehovah nissi (ìbà rẹ ó)
Yahwey, yah Jehovah o (ìbà rẹ ó-o)
Woss, ọba atobajaye
Jésù sama gbohun l'ẹnu mi o (oya Jésù iba)
Ní mọ ṣe sọ wípé, Ọlọrun ayé mi (èmi yọ sí ọ)
Torí ore rẹ ó yeah (ore rẹ lo dá mi)
Lo dá mi si, lo dá mi sì sibẹ (dá mi sì sibẹ)
Ayajọ ọjọ ibi mi re (ayajọ ibi mi tun de)
Ayajọ ibi mi ò tun de, mo súre fún ọjọ taa bí mi
Lọ jẹkin sope
Emi yio gbé ọ ga (títí ayé, títí ayé)
Ọlọrun alágbára yea
L'arin ọpọ ènìyàn (yea-yea-yea)
Emi yio gbé ọ ga, èmi ó gbé ọ ga o
Emi yio gbé ọ ga (torí ibi gíga lọ ń gbé)
Olọrun alágbára (gíga-gíga l'órúkọ rẹ ó)
L'arin ọpọ ènìyàn (ọpọ ènìyàn, o yea)
Emi ó gbé ọ ga o
Lase wan nsọ pé, baba oku iṣẹ
Jesu oku iṣẹ ó, Ọlọrun àgbàlagbà-a
Ọba àdáni má gbàgbé ẹni ó, oku iṣẹ (bàbá mi)
Oku iṣẹ ó yea
Baba okú iṣẹ (Jesu oku iṣẹ)
Jesu oku iṣẹ ó (ẹsẹ ibi tẹ tí bẹrẹ, ibi tẹ ba de)
Ọlọ́run àgbàlagbà (ọba adani)
Ọba adani má gbàgbé ẹni
Jesu oku iṣẹ (Jesu oku iṣẹ ó)
Woss, ìwọ to fẹ wá la o má sin títí
Olúwa olóore wá, ọba to gbàwá ninu ìdánwò ayé
Ọkan l'ana, ọkan l'oni, ọkan títí ayérayé
Jesu, awa sope ó yeah (ẹsẹ)
Nípa ìfẹ olùgbàlà, mọ d'ọmọ ọga ogo, mo dẹ ni pataki
Torí na bí mo ba ji lo wurọ kutu, ma d'ori mi mú yea
Mo se orí re ó, alẹdami mo dúpẹ ó
Orí re ìràpadà ó (mo'se orí re ó, alẹdami mo dúpẹ ó
Orí re ore ọfẹ, nítorí na
Oyẹ kin jó fún bàbá mi
Oyẹ kin k'ọrin fún bàbá mi o yea
Oyẹ kin jó fún bàbá mi oh-oh
Fún gbogbo ore to se mi oh
Oyẹ kin jó fún bàbá mi (ore ọfẹ rẹ pọ pupọ)
Oyè kin kọrin fún bàbá mi (ijo ọpẹ mo ń jó)
Oyẹ kin jó fún bàbá mi (fún gbogbo ore)
Fún gbogbo ore to se mi oh
Ní mọ ṣe ni, Olúwa lemi ofi ìyìn fún, modupẹ mo yege
Hey-hey, mukulu-mukẹ má jo s'ọlọrun mi
Tó ba jẹ bẹ, ó mùkúlú (ọ mukẹkẹ)
O mùkúlú (ọ mukẹkẹ)
O mùkúlú (ọ mukẹkẹ)
O mukẹkẹ (ọ mukẹkẹ)
Ijó ọpẹ mi múkulu (ọ mukẹkẹ)
Mùkúlú, mùkúlú, mùkúlú, mùkúlú (ọ mukẹkẹ)
Ó mùkúlú ṣẹ (ọ mukẹkẹ)
O mukẹkẹ (ọ mukẹkẹ)
Aní ìwọ to fẹ wa la o ma sìn títí
Olúwa olóore wá, awa sọ wipe ó yea (ose ó-ó)
Credits
Writer(s): Emmanuel Edunjobi
Lyrics powered by www.musixmatch.com
Link
Disclaimer:
i testi sono forniti da Musixmatch.
Per richieste di variazioni o rimozioni è possibile contattare
direttamente Musixmatch nel caso tu sia
un artista o
un publisher.