Testo Alimanjiri - BhadBoi OML
Testo della canzone Alimanjiri (BhadBoi OML), tratta dall'album Bhad Boi
(Aṣalamalaikun, alimanjiri al sẹlibaba), (banbiala)
(Dabatun na, yi si-ni man goro ma go), (banbiala)
(Kamsẹi baba), (banbiala)
(Kamsẹi baba), (banbiala)
(Banbiala, banbia'-banbia'-banbia'-banbia)
Kar gayni wanna kolo, kar gayni wanna wansa (ah-ah)
Áshiri abo, ẹyin gan shèè'bi pe mo gbo Hausa
Asalamalaikun, alimanjiri al sẹlimama (banbiala)
Asalamalaikun, alimanjiri al sẹlipapa (banbiala)
Shèèbi you know me?
Awori no dey say wetin he no mean (uh-hn)
Shèèbi you know me? (Shèèbi you know me? Uh-uh)
Bringing life bim-pe mo gbè áyàn mi
Bringing lights to our community
I'm rocking cuban, á gb'ọmọ lo Cubana-Cubana for this hard economy
Ishẹ agbè l'afin ball, alimanjiri al sẹlimama (banbiala)
Asalamalaikun, alimanjiri al sẹlipapa (banbiala)
F'ẹjọ lẹ, do transfer, alimanjiri al sẹlimama (banbiala)
Báni baba, shinẹkọ, alimanjiri al sẹlipapa (banbiala)
Ẹ yè ma bamisọ, ẹ yè ma bamisọ ọrọ wèrèy t'ẹlè ba soldier sọh
Na'wo na'wo l'èmi na, emi ab'orogun jo, ẹ jẹn de'lè ọrẹ mi (de'lè ọrẹ mi)
Gbè'lè pa'wo, Dappеr, ọrẹ mi (Dappеr, ọrẹ mi)
Baddo, ọrẹ mi (Baddo, ọrẹ mi)
Baba Lashe Zanku, ọrẹ mi (Zanku, ọrẹ mi)
Odinaka Poco, ọrẹ mi (Poco, ọrẹ mi)
Ishẹ agbè l'afin ball, alimanjiri al sẹlimama (banbiala)
Asalamalaikun, alimanjiri al sẹlipapa (banbiala)
F'ẹjọ lẹ, do transfer, alimanjiri al sẹlimama (banbiala)
Báni baba, shinẹkọ, alimanjiri al sẹlipapa (banbiala)
Wamuhlele, wamuhlele, I no send your mama oh (uh)
Me wey no send your papa oh (uh)
Wetin be the matter oh? (Uh)
Me wey no get data
Bringing life bim-pe mo gbè áyàn mi
Bringing lights to our community
I'm rocking cuban, á gb'ọmọ lo Cubana-Cubana for this hard economy
Ishẹ agbè l'afin ball, alimanjiri al sẹlimama (banbiala)
Asalamalaikun, alimanjiri al sẹlipapa (banbiala)
F'ẹjọ lẹ, do transfer, alimanjiri al sẹlimama (banbiala)
Báni baba, shinẹkọ, alimanjiri al sẹlipapa (banbiala)
Ẹ yè ma bamisọ, ẹ yè ma bamisọ ọrọ wèrèy t'ẹlè ba soldier sọh
Na'wo na'wo l'èmi na, emi ab'orogun jo, ẹ jẹn de'lè ọrẹ mi (de'lè ọrẹ mi)
Sọ'kè d'òwò, Garry, ọrẹ mi (Garry, ọrẹ mi)
Zino', ọrẹ mi (Zino', ọrẹ mi)
Palumbo, ọrẹ mi (Palumbo, ọrẹ mi)
Fá haya, ko gbá wire (ooh)
Ishẹ agbè l'afin ball, alimanjiri al sẹlimama (banbiala)
Asalamalaikun, alimanjiri al sẹlipapa (banbiala)
F'ẹjọ lẹ, do transfer, alimanjiri al sẹlimama (banbiala)
Báni baba, shinẹkọ, alimanjiri al sẹlipapa (banbiala)
Credits
Writer(s): Olawale Adibe, Akinyinka Oladimeji
Lyrics powered by www.musixmatch.com
Link
Disclaimer:
i testi sono forniti da Musixmatch.
Per richieste di variazioni o rimozioni è possibile contattare
direttamente Musixmatch nel caso tu sia
un artista o
un publisher.