Testo Aare - Qdot

Testo della canzone Aare (Qdot), tratta dall'album Aare

Lo'gun ọfẹ
Ahoo! (Lo'gun ọfẹ)
O de o (lo'gun ọfẹ)
Ọmọ imalẹ afeleja
(Lo'gun ọfẹ, lo'gun ọfẹ, lo'gun ọfẹ)
Qdot l'orukọ mi
Irukẹrẹ ọba le ma si lọwọ mii
Tẹ ba ti ri mi, kẹ fun mi lọ̀wọ̀ mii
Mi o b'anybody ja s'ọba, ah-ah-ah
Tẹ ba ti ri mi, kẹ fun mi lọ̀wọ̀ mii (Aarẹ Ọna Kakanfo)
Ẹ bun mi lọ̀wọ̀ mi (Aarẹ Ọna Kakanfo)
Jagunjagun ni mi, ẹ ma ri mi fin (Aarẹ Ọna Kakanfo)
Akinkanju ọkunrin loju ogun (Aarẹ Ọna Kakanfo)
Wèrèpè oni'bikan ta maa gba mu (Aarẹ Ọna Kakanfo)
Ma lọ di mu, ko ma di'na mu (Aarẹ Ọna Kakanfo)
Awọn ọmọ Oduduwa mi o fi mi ṣere (Aarẹ Ọna Kakanfo)
I deserve some accolades (Aarẹ Ọna Kakanfo)
Yeah-yeah, yeah-yeah
Ẹ duro na, kẹ jẹ n sọrọ
Ẹ jẹ n sọ t'ẹnu mii
Wọn d'ohun m'agogo lẹnu
Tori kuku luku s'ewe gẹlu gẹlu
Tori a f'aja ṣọ'le
Aja p'oun l'ọba ẹkun
Ara me riri, mo r'emọ, ki lo fa t'alantakun l'eri s'alabahun?
If you don't like me, I don't like you
Forget the Yorùbá I spoke o
Ma p'agbada fun mi ni raincoat o
Mo ti jẹlọ ọ, ko s'ohun tẹ fẹ ṣe
K'aṣẹwo to ko pẹtẹsi, oju ri
Ẹ sọ f'ologini to f'oju d'ẹku
Ko mọ'ru ẹranko to maa ba ta'hun ni igbọ
Irukẹrẹ ọba le ma si lọwọ mii
Tẹ ba ti ri mi, kẹ fun mi lọ'wọ' mii
Mi o b'anybody ja s'ọba, ah-ah-ah
(Lo'gun ọfẹ, lo'gun ọfẹ)
Tẹ ba ti ri mi, kẹ fun mi lọ̀wọ̀ mii (Aarẹ Ọna Kakanfo)
Ẹ bun mi lọ̀wọ̀ mi (Aarẹ Ọna Kakanfo)
Jagunjagun ni mi, ẹ ma ri mi fin (Aarẹ Ọna Kakanfo)
Akinkanju ọkunrin loju ogun (Aarẹ Ọna Kakanfo)
Wèrèpè oni'bikan ta maa gba mu (Aarẹ Ọna Kakanfo)
Ma lọ di mu, ko ma di'na mu (Aarẹ Ọna Kakanfo)
Awọn ọmọ Oduduwa mi o fi mi ṣere (Aarẹ Ọna Kakanfo)
I deserve some accolades (Aarẹ Ọna Kakanfo)
Yeah-yeah, yeah-yeah
Ti ko ba ni idi, a ki n r'ẹja loke odo
T'ọwọ ba ti gb'owo ẹyin, ẹnu o ni le s'ododo
Before, before, I dey do like mumu for dem
Ay, dem dey do face like a Lion
Fẹlẹfẹlẹ ni wọn bi ti nylon
Yiyọ ẹkun t'ojo kọ
Ẹ maa f'ẹkọ ta'na fun mi jẹ
Kanakana ko ma na ọmọ ẹga
Agbado inu'go f'adiyẹ, awomọju ni
T'omi o ba to la ti wẹ, a fi bọ'ju ni
Don't feed me what I don't eat
The fall of a dry leaf, it's a lesson for the fresh one
Lo'gun ọfẹ o, lo'gun ọfẹ ẹ (k'ara o le, baba)
Aarẹ. Ganiyu Ige Adams
The 15th Aarẹ Ọna Kakanfo fun gbogbo Ile Yorùbá
Jagunjagun f'awọn Yorùbá (Aarẹ Ọna Kakanfo)
Ooni of Ife, Alaṣẹ igbakeji Orisa (Aarẹ Ọna Kakanfo)
Ọjaja Keji, Arole Oodua (Aarẹ Ọna Kakanfo)
Mo mọ Alaafin Ọyọ (Aare Ọna Kakanfo)
Iku baba Yeye, iku to n pa ku jẹ (Aarẹ Ọna Kakanfo)
Mo ki ijoye, Mo ki gbogbo Ọba Alade o (Aarẹ Ọna Kakanfo)
Gbogbo ọmọ Yorùbá n'ile, l'aajo (Aarẹ Ọna Kakanfo)
IBD Dende (Aarẹ Ọna Kakanfo)
Arẹmọ Oni'ru, Akin Shittu olori Ẹyọ (Aarẹ Ọna Kakanfo)
Fẹmi Jaguar, Shina Peller (Aarẹ Ọna Kakanfo)
Fuad Olotọ, Laolu Selfmade (Aarẹ Ọna Kakanfo)
Sir Kuti kogbadigi, Billy Q, El-Dubai (Climax)
Oluọmọ f'Ọlagbade wa ni Banglar-rẹ (Aarẹ Ọna Kakanfo)
Sir K, Ọlọruntoyin ni Bombay (Aarẹ Ọna Kakanfo)
Taiyeolu fo ni Toronto oo
Qdot l'orukọ mi ooo



Credits
Writer(s):
Lyrics powered by www.musixmatch.com

Link

Disclaimer: i testi sono forniti da Musixmatch.
Per richieste di variazioni o rimozioni è possibile contattare direttamente Musixmatch nel caso tu sia un artista o un publisher.

Elenco artisti

© 2026 Riproduzione riservata. Rockol.com S.r.l.
Policy uso immagini

Rockol

  • Utilizza solo immagini e fotografie rese disponibili a fini promozionali (“for press use”) da case discografiche, agenti di artisti e uffici stampa.
  • Usa le immagini per finalità di critica ed esercizio del diritto di cronaca, in modalità degradata conforme alle prescrizioni della legge sul diritto d'autore, utilizzate ad esclusivo corredo dei propri contenuti informativi.
  • Accetta solo fotografie non esclusive, destinate a utilizzo su testate e, in generale, quelle libere da diritti.
  • Pubblica immagini fotografiche dal vivo concesse in utilizzo da fotografi dei quali viene riportato il copyright.
  • È disponibile a corrispondere all'avente diritto un equo compenso in caso di pubblicazione di fotografie il cui autore sia, all'atto della pubblicazione, ignoto.

Segnalazioni

Vogliate segnalarci immediatamente la eventuali presenza di immagini non rientranti nelle fattispecie di cui sopra, per una nostra rapida valutazione e, ove confermato l’improprio utilizzo, per una immediata rimozione.