Testo Tension - Tiphe feat. Niphkeys & YKB
Testo della canzone Tension (Tiphe feat. Niphkeys & YKB), tratta dall'album Tension (Remix) - Single
Nope
No word, Ginit
You don't know the streets like we do
Nope (Niphkeys)
Igi to ba mu ọmọ ile iwe sa nigbo o
Awa dẹ ma tension wọn mọta wa ni jo
K'awa ṣá ma wo wọn ni iran, ka ma carry go
Emi ọmọ ara má sanwo, ki n le tun duro wo?
Ayy, awa l'agba, ki lo ṣe àwọn ṣẹ-ṣẹ de yi?
Awa lọ mọ, ibajẹ wọn ko le stain mi
Awa l'agba o, mi o ṣe àwọn ṣẹ-ṣẹ de yi o
Awa l'agba, ki lo ṣe àwọn ṣẹ-ṣẹ de yi?
Nobody can't chance me, emi dẹ ma carry go (lati bo sibo?)
Awa o dẹ le fọ fun wọn, ọmọ ita wa ni gbo (egbe-gbe-gbe-gbe)
K'awa ṣá ma wo wọn niran, ka ma carry go
K'awa ṣá ma wo wọn, k'awa ṣá ma wo wọn o
Ahn-ahn, fi lẹ bẹ, make them talk
Ṣébí na why we get am
I go dance, I go flex
Ṣébí na why we get am
No comedy-dy, what I no get
Ki lo ṣe àwọn nonetity? (Eh)
Them dey call me celebrity, eh
But I be bulldozer (ah-ah)
I no get pretty Q (I be bulldozer)
Ọgbẹni, commot for road
Awa l'agba (yeah), ki lo ṣe àwọn ṣẹ-ṣẹ de yi?
Awa lọ mọ, ibajẹ wọn ko le stain mi
Awa lọ mọ o, ki lo ṣe àwọn ṣẹ-ṣẹ de yi o?
Awa l'agba (yeah), ki lo ṣe àwọn ṣẹ-ṣẹ de yi?
Nobody can't chance me, emi dẹ ma carry go (lati bo sibo?)
Awa o dẹ le fọ fun wọn, mọta wa ni gbo (e gbe, gbe, gbe)
K'awa ṣá ma wo wọn niran, ka ma carry go o
K'awa ṣá ma wo wọn, k'awa ṣá ma wo wọn o
K'awa ṣá ma wo wọn, k'awa ṣá ma wo wọn o
Oh, ah, Kila fagbo ẹlẹyin, ahn-ahn
Kila n fagbo ẹlẹyin mi oke o
Kila fagbo ẹlẹyin mi oke o
'Sufu baby, ta ba sin wọn d'oke
Yusufu, baby o, a maa sin wọn de oke o
(Boombah)
Credits
Writer(s): Yusuf Oluwo, Adebajo Oluwanifemi Adebanjo, Adebayo Abiodun Abraham, Oyedotun Emmanuel Oluwatobiloba
Lyrics powered by www.musixmatch.com
Link
Disclaimer:
i testi sono forniti da Musixmatch.
Per richieste di variazioni o rimozioni è possibile contattare
direttamente Musixmatch nel caso tu sia
un artista o
un publisher.