Rockol30

Testo Idi Oremi - Naira Marley

Testo della canzone Idi Oremi (Naira Marley), tratta dall'album Idi Oremi (Opotoyi, Pt. 2)

Yo!
Yo, Rexxie 'pon this one
Aiye le, aiye akamara
Wọn fẹ sọ mi da ki n ṣe da
Ani, ọpẹlọpẹ camera
A ba ma mọ pe ẹyin naa wa
Mo ni, "Ẹ dakun, ẹ maa sọ bẹẹ mọ" (ẹ maa sọ bẹẹ mọ)
Bo ọrẹ o ki n jẹ ṣẹ ọrẹ (bo ọrẹ o ki n jẹ ṣẹ ọrẹ)
Ọrẹ ma n je'ṣẹ ọrẹ (ọrẹ ma n je'ṣẹ ọrẹ)
Ọrẹ n maa gbọ'ṣẹ ọrẹ (ọrẹ ma n ja'ṣẹ ọrẹ)
Jẹ ka ma ri ra wa (jẹ ka ma ri ra wa)
Jẹ ka ma gbọ ra wa (jẹ ka ma gbọ ra wa)
Jẹ ka ma ṣa ra wa (jẹ ka ma ṣa ra wa)
Jẹ ka ma fọ ra wa (jẹ ka ma fọ ra wa)
Ṣo'ko lo dun to yẹn (ṣo'ko lo dun to yẹn)
O ma ti pe mi pa (o ma ti pe mi pa)
Ki la pe ra wa ni ọrẹ fun? (Ki la pe ra wa ni ọrẹ fun)
Ti n ba le mu yẹn pa (ti n ba le gbọ yẹn pa)
Idi ọrẹ mi ni emi o fi si (ay-ay)
Idi ọrẹ mi o pọ toyi (idi ọrẹ mi o pọ toyi)
Idi ọrẹ mi o fẹ to yi (idi ọrẹ mi o fẹ to yi)
Idi ọrẹ mi o pọ toyi (idi ọrẹ mi o pọ toyi)
Yea, o ro boya mo ti ku (o ro boya mo ti ku)
O ro boya ma ti sun (o ro boya ma ti sun)
O wa fẹ fun di mi (o wa fẹ fun di mi)
O wa fẹ wo idi mi (o wa fẹ wo idi mi)
O fẹ ma taka mi (o fẹ ma taka mi)
Ṣo le ba mi taka ni? (Mi o le ba ẹ taka o)
Ti n ba ju banga mi (ti n ba ju banga mi)
Igboro ma gbadun mi (igboro a gbadun mi)
O fẹ ma yi'wọ (o fẹ ma yi'wọ)
O fẹ ma da'wọ ru (o fẹ ma da'wọ ru)
O da pe o ti n d'oko nta (ay-ay)
Set awọn Okon'ta (set awọn Okon'ta)
O fẹ ma lamba mi (o fẹ ma lamba mi)
Ṣe mo jọ Zlatan ni? (Ṣe mo jọ Zlatan ni)
O fẹ ma flatter mi (o fẹ ma flatter mi)
O fẹ ma d'ọgbọn mu Fanta mi (o fẹ ma d'ọgbọn mu Fanta mi)
Mo fun l'ọyan ko n ṣe mother mi
O pe mi zaddy, ko n ṣe daughter mi (ko n ṣe daughter mi)
Pa de mi ni Gaza mi (pa de mi ni Gaza mi)
Ma gbagbe ganja mi (ma gbagbe ganja mi)
Tunde Fashola ni brother mi (ay-ay)
Wọn ni fi ẹlomi ṣe mother mi (ay-ay)
Mo ti mu ọyan mummy mi (mo ti mu ọyan mummy mi)
Mo ti ri ọyan mummy mi (mo ti ri ọyan mummy mi)
Mo ni pe ẹ mọ mẹmẹ (mẹmẹ)
Tẹ ba mọ mẹmẹ, ẹ mo mẹmẹmẹ (mẹmẹmẹ)
Tẹ ba mo mẹmẹ, ẹ mo mẹmẹmẹmẹ
Tẹ ba mọ mẹmẹmẹ, ẹ mọ mẹmẹmẹmẹmẹmẹ
Idi ọrẹ mi ni emi o fi si (ay-ay)
Idi ọrẹ mi o pọ toyi (idi ọrẹ mi o pọ toyi)
Idi ọrẹ mi o fẹ to yi (idi ọrẹ mi o fẹ to yi)
Idi ọrẹ mi o pọ toyi (idi ọrẹ mi o pọ toyi)
Ay, idi ọrẹ mi l'emi o fi si, jọọ (ay-ay)
Idi ọrẹ mi o pọ toyi (idi ọrẹ mi o pọ toyi)
Idi ọrẹ mi o fẹ to yi (idi ọrẹ mi o fẹ to yi)
Idi ọrẹ mi o pọ toyi (idi ọrẹ mi o pọ toyi)
Ay, to ba sure fun ẹ, bọ gbangban (gbangban)
Ṣebi o lo mọ idi gbọn dada (dada)
O ṣe, ọrẹ mi oni idi nla
Ṣe emi ati ẹ le ma jọ tungba? (Tungba)
Ṣe idi ẹ re abi o wọ pampers?
Mad! your ass they give me asthma
Ha, mo ni ko send number
Ha, why did you send aza?
Ṣe idi ẹ re abi o d'ọgbọn si?
Jẹ n fa na, Jẹ n f'oko si
Mo ṣe one hour, o ni o fẹ si (o ni o fẹ si)
Igba ta ṣe tan o pe mi ni bestie (o pe mi ni bestie)
Ha, what kind of bestie is that? (What kind of bestie is that?)
Mo fun bestie pussy massage (pussy massage)
Bẹẹru Ọlọhun, Taqwa la (bẹẹru Ọlọhun, Taqwa la)
Ẹ sọ'ko fun Shaytan (ẹ sọ'ko fun Shaytan)
Bi mo n ṣe l'orita, o da pe ẹ ti n jẹ Semovita
O da pe ori ẹ fẹ ko j'iya
O da pe iwọ ọmọ yi ti n ni liver (anyways)
Idi ọrẹ mi ni emi o fi si (ay-ay)
Idi ọrẹ mi o pọ toyi (idi ọrẹ mi o pọ toyi)
Idi ọrẹ mi o fẹ to yi (idi ọrẹ mi o fẹ to yi)
Idi ọrẹ mi o pọ toyi (idi ọrẹ mi o pọ toyi)
Ay, idi ọrẹ mi l'emi o fi si, jọọ (ay-ay)
Idi ọrẹ mi o pọ toyi (idi ọrẹ mi o pọ toyi)
Idi ọrẹ mi o fẹ to yi (idi ọrẹ mi o fẹ to yi)
Idi ọrẹ mi o pọ toyi (idi ọrẹ mi o pọ toyi) (yeah)
(Spyrit Mix)



Credits
Writer(s): Chisom Ezeh, Azeez Adeshina Fashola
Lyrics powered by www.musixmatch.com

Link

Disclaimer: i testi sono forniti da Musixmatch.
Per richieste di variazioni o rimozioni è possibile contattare direttamente Musixmatch nel caso tu sia un artista o un publisher.

Elenco artisti

© 2025 Riproduzione riservata. Rockol.com S.r.l.
Policy uso immagini

Rockol

  • Utilizza solo immagini e fotografie rese disponibili a fini promozionali (“for press use”) da case discografiche, agenti di artisti e uffici stampa.
  • Usa le immagini per finalità di critica ed esercizio del diritto di cronaca, in modalità degradata conforme alle prescrizioni della legge sul diritto d'autore, utilizzate ad esclusivo corredo dei propri contenuti informativi.
  • Accetta solo fotografie non esclusive, destinate a utilizzo su testate e, in generale, quelle libere da diritti.
  • Pubblica immagini fotografiche dal vivo concesse in utilizzo da fotografi dei quali viene riportato il copyright.
  • È disponibile a corrispondere all'avente diritto un equo compenso in caso di pubblicazione di fotografie il cui autore sia, all'atto della pubblicazione, ignoto.

Segnalazioni

Vogliate segnalarci immediatamente la eventuali presenza di immagini non rientranti nelle fattispecie di cui sopra, per una nostra rapida valutazione e, ove confermato l’improprio utilizzo, per una immediata rimozione.