Testo Agolo - Angelique Kidjo feat. AMÉMÉ
Testo della canzone Agolo (Angelique Kidjo feat. AMÉMÉ), tratta dall'album Agolo (Next Gen) - Single
Agolo, oh
Agolo, oh
Mo ri o, o ri o, Ọlajumọkẹ n lọ
Ọlajumọkẹ, Ọlajumọkẹ n lọ
Mo ri o, o ri o, Ọlajumọkẹ n lọ
Ọlajumọkẹ, Ọlajumọkẹ n lọ
Mo ri o, o ri o, Ọlajumọkẹ n lọ
Ọlajumọkẹ, Ọlajumọkẹ n lọ
Mo ri o, o ri o, Ọlajumọkẹ n lọ
Ọlajumọkẹ, Ọlajumọkẹ n lọ
Ẹ ma ṣe foya léni
Ifẹ fun gbogbo ayé
Ẹ ma ṣe gbagbe ifẹ
Ifẹ fun ilẹ baba wa
Ifẹ ayé ilé (ayé)
Igbadun fun ayé
Ifẹ ayé ilé (ayé)
Igbadun fun ayé
Ọlajumọkẹ n lọ
Ọlajumọkẹ n lọ
Ọlajumọkẹ n lọ
Ọlajumọkẹ n lọ (agolo oh)
Ọlajumọkẹ n lọ
Ọlajumọkẹ n lọ
Ọlajumọkẹ n lọ
Ọlajumọkẹ n lọ (agolo)
Mo ri o, o ri o, Ọlajumọkẹ n lọ
Ọlajumọkẹ, Ọlajumọkẹ n lọ
Mo ri o, o ri o, Ọlajumọkẹ n lọ
Ọlajumọkẹ, Ọlajumọkẹ n lọ (agolo oh)
Mo ri o, o ri o, Ọlajumọkẹ n lọ
Ọlajumọkẹ, Ọlajumọkẹ n lọ
Mo ri o, o ri o, Ọlajumọkẹ n lọ
Ọlajumọkẹ, Ọlajumọkẹ n lọ
Ẹ ma ṣe foya léni
Ifẹ fun gbogbo ayé
Ẹ ma ṣe gbagbe ifẹ
Ifẹ fun ilẹ baba wa
Ifẹ ayé ilé (ayé)
Igbadun fun ayé
Ifẹ ayé ilé (ayé)
Igbadun fun ayé
Ifẹ ayé ilé (agolo, oh)
Igbadun fun ayé (agolo, oh)
Ifẹ ayé ilé
Igbadun fun ayé
Ifẹ ayé ilé (agolo, oh)
Igbadun fun ayé
Ifẹ ayé ilé (ayé)
Ilé, ilé, ilé, ilé, ilé
Oh-oh-oh-oh-oh-oh, eh-eh-eh-eh
Ilé, ilé
Ifẹ, ilé, ifẹ, ilé-
Ilé, ilé
Ọlajumọkẹ n lọ
Ọlajumọkẹ n lọ
Ọlajumọkẹ n lọ
Ọlajumọkẹ n lọ
Mo ri o, o ri o, Ọlajumọkẹ n lọ
Ọlajumọkẹ, Ọlajumọkẹ n lọ
Mo ri o, o ri o, Ọlajumọkẹ n lọ
Ọlajumọkẹ, Ọlajumọkẹ n lọ
Mo ri o, o ri o, Ọlajumọkẹ n lọ
Ọlajumọkẹ, Ọlajumọkẹ n lọ
Mo ri o, o ri o, Ọlajumọkẹ n lọ
Ọlajumọkẹ, Ọlajumọkẹ n lọ
Mo ri o, o ri o, Ọlajumọkẹ n lọ (agolo oh)
Ọlajumọkẹ, Ọlajumọkẹ n lọ
Mo ri o, o ri o, Ọlajumọkẹ n lọ
Ọlajumọkẹ, Ọlajumọkẹ n lọ
Mo ri o, o ri o, Ọlajumọkẹ n lọ
Ọlajumọkẹ, Ọlajumọkẹ n lọ
Mo ri o, o ri o, Ọlajumọkẹ n lọ
Ọlajumọkẹ, Ọlajumọkẹ n lọ
Credits
Writer(s): Angelique Kidjo, Jean Louis Pierre Hebrail
Lyrics powered by www.musixmatch.com
Link
Disclaimer:
i testi sono forniti da Musixmatch.
Per richieste di variazioni o rimozioni è possibile contattare
direttamente Musixmatch nel caso tu sia
un artista o
un publisher.
Ultimi articoli
Chi sono Les Amazones d'Afrique? Esce l'album "République Amazone". VIDEO
(25/03/2017)
Torna Angélique Kidjo, è 'Eve' il nuovo album
(23/10/2013)
Angelique Kidjo: è 'ÖΫÕ' il nuovo album
(04/11/2009)
Angelique Kidjo dal vivo in Italia
(16/07/2008)
Nuovo album per Angelique Kidjo
(05/04/2007)
Pronto il nuovo CD di Angélique Kidjo (con Tony Visconti e Peter Gabriel)
(29/01/2007)
Angelique Kidjo: «La Francia è razzista»
(23/11/1998)